ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb20 November ojú ìwé 4
  • Ohun Tó Dáa Jù Ni Kó O Fún Jèhófà

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ohun Tó Dáa Jù Ni Kó O Fún Jèhófà
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Fún Jèhófà Ní Ohun Tó Dára Jù Lọ
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
  • “Màá Wà Pẹ̀lú Rẹ Bí O Ṣe Ń Sọ̀rọ̀”
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
  • Àwọn Ẹbọ Ìyìn Tí Inú Jèhófà Dùn Sí
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2000
  • Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
    Jí!—2022
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
mwb20 November ojú ìwé 4
Àwòrán: Jèhófà gbà káwọn ọmọ Ísírẹ́lì mú oríṣiríṣi nǹkan wá láti fi rúbọ. 1. Ìyẹ̀fun tó kúnná. 2. Ẹyẹlé. 3. Ìdílé kan mú àgùntàn lọ fún àlùfáà.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | LÉFÍTÍKÙ 4-5

Ohun Tó Dáa Jù Ni Kó O Fún Jèhófà

5:5-7, 11

Kò sẹ́ni tí ò lè mú nǹkan wá láti fi rúbọ sí Jèhófà nígbà ayé àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, títí kan àwọn tálákà. Kódà kẹ́ni kan jẹ́ òtòṣì paraku, ó ṣì máa rí ohun táá mú wá fún Jèhófà, tó bá ṣáà ti jẹ́ ohun tó dáa jù ló mú wá. Ẹnì náà lè fi ìyẹ̀fun rúbọ, àmọ́ Jèhófà retí pé kó jẹ́ ìyẹ̀fun tó “kúnná,” irú èyí tí wọ́n máa ń lò fún àwọn àlejò pàtàkì. (Jẹ 18:6) Lónìí, Jèhófà máa ń tẹ́wọ́ gba “ẹbọ ìyìn” wa, kódà tó bá tiẹ̀ jẹ́ pé nǹkan kékeré la lè ṣe nítorí ipò tá a wà. Tó bá ṣáà ti jẹ́ pé ohun tó dáa jù la ṣe, inú Jèhófà máa dùn sí i.​—Heb 13:15.

Báwo ni ohun tá a mọ̀ yìí ṣe jẹ́ kí ọkàn wa balẹ̀ pé Jèhófà mọyì ohun tá à ń ṣe, tí àìlera ò bá jẹ́ ká lè ṣe tó bá a ṣe ń ṣe tẹ́lẹ̀?

Àwòrán: Àwọn arábìnrin méjì ń lo ohun ìní wọn tó dára jù lọ láti fi rú ‘ẹbọ ìyìn’ sí Jèhófà. 1. Arábìnrin kan tó ń sìn níbi tí wọ́n ti ń sọ èdè àjèjì ń wàásù fún obìnrin kan nínú ọjà. 2. Arábìnrin àgbàlagbà kan ń kọ lẹ́tà nínú ilé rẹ̀.
    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́