ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 March ojú ìwé 13
  • Máa Lo Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Máa Lo Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Máa Lo Ìbéèrè
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Jẹ́ Kí Ọ̀rọ̀ Rẹ Wọni Lọ́kàn
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Jẹ́ Kí Jèhófà Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́ Nípasẹ̀ Àdúrà
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Ran Àwọn Tó Ò Ń Kọ́ Lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Lọ́wọ́ Láti Jáwọ́ Nínú Ìwà Àìmọ́
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 March ojú ìwé 13

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ | JẸ́ KÍ IṢẸ́ SÍSỌNI DI ỌMỌ Ẹ̀YÌN MÁA FÚN Ẹ LÁYỌ̀

Máa Lo Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run

Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run lágbára! (Heb 4:12) Kódà, ó lè wọ àwọn tí kò mọ Ọlọ́run lọ́kàn. (1Tẹ 1:9; 2:13) Inú wa máa ń dùn gan-an tá a bá rí bí ẹni tá à ń kọ́ lẹ́kọ̀ọ́ ṣe ń mọyì ohun tuntun tó ń kọ́ látinú Bíbélì.

Ẹ WO FÍDÍÒ NÁÀ JẸ́ KÍ IṢẸ́ SÍSỌNI DI ỌMỌ Ẹ̀YÌN MÁA FÚN Ẹ LÁYỌ̀​—TÚBỌ̀ JÁ FÁFÁ​—JẸ́ KÍ ÀWỌN ÈÈYÀN RÍ AGBÁRA TÍ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN NÍ, KẸ́ Ẹ SÌ DÁHÙN ÀWỌN ÌBÉÈRÈ YÌÍ:

  • Àwòrán látinú fídíò ‘Jẹ́ Kí Iṣẹ́ Sísọni Di Ọmọ Ẹ̀yìn Máa Fún Ẹ Láyọ̀​—Túbọ̀ Já Fáfá​—Jẹ́ Kí Àwọn Èèyàn Rí Agbára Tí Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Ní.’ Neeta tẹ́tí sílẹ̀ nígbà tí Jade ń ka Bíbélì.

    Kí ni Neeta sọ tó jẹ́ kí Jade rí i pé ó bọ́gbọ́n mú kí wọ́n ká Bíbélì?

  • Àwòrán látinú fídíò ‘Jẹ́ Kí Iṣẹ́ Sísọni Di Ọmọ Ẹ̀yìn Máa Fún Ẹ Láyọ̀​—Túbọ̀ Já Fáfá​—Jẹ́ Kí Àwọn Èèyàn Rí Agbára Tí Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Ní.’ Jade ń ka Bíbélì sókè.

    Báwo ni Neeta ṣe jẹ́ kí Jade rí agbára tí Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ní nígbà tó ní kí Jade ka ẹsẹ Bíbélì yẹn sókè, tó sì mẹ́nu kan kókó pàtàkì tó wà níbẹ̀?

  • Àwòrán látinú fídíò ‘Jẹ́ Kí Iṣẹ́ Sísọni Di Ọmọ Ẹ̀yìn Máa Fún Ẹ Láyọ̀​—Túbọ̀ Já Fáfá​—Jẹ́ Kí Àwọn Èèyàn Rí Agbára Tí Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Ní.’ Jade rẹ́rìn ín músẹ́ sí Neeta.

    Kí ló fi hàn pé ẹsẹ Bíbélì yẹn wọ Jade lọ́kàn, báwo nìyẹn sì ṣe rí lára Neeta?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́