ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 September ojú ìwé 9
  • Ohun Tá A Rí Kọ́ Látinú Ìtàn Àwọn Ará Gíbíónì

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ohun Tá A Rí Kọ́ Látinú Ìtàn Àwọn Ará Gíbíónì
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Àwọn Ará Gíbéónì Ọlọgbọ́n
    Ìwé Ìtàn Bíbélì
  • Jóṣúà àti Àwọn Ará Gíbíónì
    Àwọn Ẹ̀kọ́ Tó O Lè Kọ́ Látinú Bíbélì
  • Jèhófà Jà Fáwọn Ọmọ Ísírẹ́lì
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Ìmọ̀ràn Tí Jóṣúà Fún Àwọn Ọmọ Ísírẹ́lì Kẹ́yìn
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 September ojú ìwé 9
Àwòrán: Oríṣiríṣi iṣẹ́ ni wọ́n yàn fáwọn ará Gíbíónì. 1. Ọkùnrin kan ń kó igi. 2. Ọkùnrin kan ń di igi. 3. Ọkùnrin kan ń fi àjàgà gbé omi.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Ohun Tá A Rí Kọ́ Látinú Ìtàn Àwọn Ará Gíbíónì

Àwọn ará Gíbíónì fi hàn pé àwọn jẹ́ ọlọ́gbọ́n (Joṣ 9:3-6; it-1 930-931)

Àwọn àgbààgbà Ísírẹ́lì ò hùwà ọgbọ́n, torí wọn ò wádìí lọ́dọ̀ Jèhófà (Joṣ 9:14, 15; w11 11/15 8 ¶14)

Onírẹ̀lẹ̀ làwọn ará Gíbíónì, wọ́n gbà láti máa ṣiṣẹ́ sin àwọn ọmọ Ísírẹ́lì (Joṣ 9:25-27; w04 10/15 18 ¶14)

Àwọn ará Gíbíónì gbà láti ṣiṣẹ́ tó rẹlẹ̀, torí pé wọ́n fẹ́ rí ojúure Jèhófà. Báwo là ṣe lè fi hàn pé a jẹ́ onírẹ̀lẹ̀ bíi tiwọn?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́