ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 November ojú ìwé 2
  • Jèhófà Fọgbọ́n Pín Ilẹ̀ Fáwọn Èèyàn Rẹ̀

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Jèhófà Fọgbọ́n Pín Ilẹ̀ Fáwọn Èèyàn Rẹ̀
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Jèhófà Jà Fáwọn Ọmọ Ísírẹ́lì
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Dáàbò Bo Ogún Iyebíye Tí Jèhófà Fún Ẹ
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Ìmọ̀ràn Tí Jóṣúà Fún Àwọn Ọmọ Ísírẹ́lì Kẹ́yìn
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Jèhófà Fẹ́ Káwọn Èèyàn Rẹ̀ Yàtọ̀
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 November ojú ìwé 2
Àwòrán: 1. Kí Jékọ́bù tó kú, ó ń sọ ohun tó máa ṣẹlẹ̀ sáwọn ọmọ rẹ̀. 2. Àwòrán Ilẹ̀ Ìlérí tó jẹ́ ká mọ ibi tí wọ́n pín fún ẹ̀yà méjìlá Ísírẹ́lì.

Jékọ́bù ń sọ ohun tá ṣẹlẹ̀ sáwọn ọmọ rẹ̀ lọ́jọ́ iwájú

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Jèhófà Fọgbọ́n Pín Ilẹ̀ Fáwọn Èèyàn Rẹ̀

Kèké ni Jèhófà lò láti fún àwọn èèyàn rẹ̀ nítọ̀ọ́ni, bóyá láti mọ ibi tí wọ́n máa pín fún ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan (Joṣ 18:10; it-1 359 ¶1)

Jèhófà rí i pé àsọtẹ́lẹ̀ tí Jékọ́bù sọ kó tó kú nímùúṣẹ (Joṣ 19:1; it-1 1200 ¶1)

Jèhófà jẹ́ káwọn èèyàn náà pinnu bí ilẹ̀ tí wọ́n máa pín fún ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan á ṣe pọ̀ tó (Joṣ 19:9; it-1 359 ¶2)

Wọ́n pín ilẹ̀ náà lọ́nà tí wọn ò fi ní máa jowú ara wọn tàbí bára wọn jà. Kí nìyẹn jẹ́ ká mọ̀ nípa bí Jèhófà ṣe máa ṣètò nǹkan nínú ayé tuntun?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́