ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb22 January ojú ìwé 5
  • Àwọn Ohun Tí Jèhófà Dá Jẹ́ Kó Túbọ̀ Dá Wa Lójú Pé Ọlọ́gbọ́n Ni

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àwọn Ohun Tí Jèhófà Dá Jẹ́ Kó Túbọ̀ Dá Wa Lójú Pé Ọlọ́gbọ́n Ni
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Bí Oyin Ṣe Ń Fò Láìka Atẹ́gùn Tó Le Sí
    Ta Ló Ṣiṣẹ́ Àrà Yìí?
  • Báwo Ni Àwọn Èèrà Ṣe Ń Rìn Láìsí Sún Kẹẹrẹ Fà Kẹẹrẹ?
    Ta Ló Ṣiṣẹ́ Àrà Yìí?
  • Àwọn Ọmọ Ogun Tó Ń Yan Lọ!
    Jí!—2003
  • Ògbógi Nínú Pípalẹ̀ Pàǹtírí Mọ́
    Jí!—2002
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
mwb22 January ojú ìwé 5
Àwòrán: 1. Àwọn èèrà ń kó ewé lọ. 2. Oyin ń fò lọ síbi òdòdó.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Àwọn Ohun Tí Jèhófà Dá Jẹ́ Kó Túbọ̀ Dá Wa Lójú Pé Ọlọ́gbọ́n Ni

Ṣé gbogbo ìgbà ni Jèhófà máa ń mọ ohun tó dáa jù fún wa? Bẹ́ẹ̀ ni! Tó bá jẹ́ bẹ́ẹ̀, ohun tó bọ́gbọ́n mu fún wa ni pé ká máa tẹ̀ lé ìtọ́sọ́nà rẹ̀. (Owe 16:3, 9) Àmọ́ nígbà míì, ó lè ṣòro fún wa láti tẹ̀ lé ìtọ́sọ́nà rẹ̀ tí ohun tí Jèhófà sọ bá yàtọ̀ sí èrò wa. Tá a bá ń ronú lórí àwọn nǹkan tí Jèhófà dá, á túbọ̀ dá wa lójú pé ọgbọ́n rẹ̀ ò láfiwé.​—Owe 30:24, 25; Ro 1:20.

Ẹ WO FÍDÍÒ NÁÀ TA LÓ ṢIṢẸ́ ÀRÀ YÌÍ? BÁWO NI ÀWỌN ÈÈRÀ ṢE Ń RÌN LÁÌSÍ SÚN KẸẸRẸ FÀ KẸẸRẸ? KẸ́ Ẹ SÌ DÁHÙN ÀWỌN ÌBÉÈRÈ YÌÍ:

  • Kí làwọn èèrà sábà máa ń ṣe lójoojúmọ́?

  • Kí làwọn èèrà máa ń ṣe kó má bàa sí sún kẹẹrẹ fà kẹẹrẹ?

  • Kí làwa èèyàn lè rí kọ́ látinú bí àwọn èèrà ṣe ń rìn láìsí sún kẹẹrẹ fà kẹẹrẹ?

Ẹ WO FÍDÍÒ NÁÀ TA LÓ ṢIṢẸ́ ÀRÀ YÌÍ? BÍ OYIN ṢE Ń FÒ LÁÌKA ATẸ́GÙN TÓ LE SÍ, KẸ́ Ẹ SÌ DÁHÙN ÀWỌN ÌBÉÈRÈ YÌÍ:

  • Ìṣòro wo làwọn tó ń wa ọkọ̀ òfuurufú kékeré máa ń ní?

  • Kí làwọn oyin máa ń ṣe tí wọ́n bá ń fò tí atẹ́gùn kì í fi í gbé wọn kiri?

  • Kí làwọn èèyàn ń ronú láti ṣe lọ́jọ́ iwájú bí wọ́n ṣe ń wo ọ̀nà tí oyin gbà ń fò?

Àwọn nǹkan wo lò ń rí láyìíká rẹ tó jẹ́ kó o gbà pé ọlọ́gbọ́n ni Jèhófà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́