ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb22 March ojú ìwé 4
  • “Ogun Náà Jẹ́ Ti Jèhófà”

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • “Ogun Náà Jẹ́ Ti Jèhófà”
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • “Ti Jèhófà Ni Ìjà Ogun Náà”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde)—2016
  • Ǹjẹ́ O Rántí?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2016
  • Ǹjẹ́ O Rántí?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2016
  • Jẹ́ Onírẹ̀lẹ̀ Tó O Bá Ṣàṣeyọrí
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
mwb22 March ojú ìwé 4
Gòláyátì dúró sẹ́yìn ẹni tó bá a gbé apata, ó sì ń fi Dáfídì ṣe yẹ̀yẹ́.

Dáfídì kojú Gòláyátì

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

“Ogun Náà Jẹ́ Ti Jèhófà”

Ohun tí Dáfídì mọ̀ nípa Jèhófà àtàwọn ohun tó ti ṣe fún un ló jẹ́ kí ìgbàgbọ́ rẹ̀ lágbára (1Sa 17:36, 37; wp16.5 11 ¶2-3)

Dáfídì ò wo bí òun ṣe kéré lẹ́gbẹ̀ẹ́ Gòláyátì. Kàkà bẹ́ẹ̀, ńṣe ló wo bí Gòláyátì ṣe kéré lẹ́gbẹ̀ẹ́ Jèhófà (1Sa 17:45-47; wp16.5 11-12)

Jèhófà mú kí Dáfídì ṣẹ́gun ọ̀tá kan tó lágbára tó sì ń bani lẹ́rù (1Sa 17:48-50; wp16.5 12 ¶4; wo àwòrán iwájú ìwé)

Ọkùnrin kan ju páálí sìgá sínú ibi ìkólẹ̀sí.

Nígbà míì, a máa ń kojú àwọn ìṣòro tó le. Bí àpẹẹrẹ, a lè máa kojú inúnibíni tàbí ká máa sapá láti jáwọ́ nínú ìwà burúkú kan. Àwọn ìṣòro yìí lè dà bí òkè lójú wa, àmọ́ ká máa rántí pé àwọn ìṣòro náà kéré ní ìfiwéra pẹ̀lú agbára tí ò láàlà tí Jèhófà ní.​—Job 42:1, 2.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́