ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb22 March ojú ìwé 12
  • Fi Sùúrù Dúró De Jèhófà

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Fi Sùúrù Dúró De Jèhófà
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Jẹ́ Onírẹ̀lẹ̀ Tó O Bá Ṣàṣeyọrí
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Ọgbọ́n Tí Dáfídì Dá Kó lè Dáàbò Bo Àwọn Èèyàn Ọlọ́run
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Ìtàn Tó Ń Mórí Ẹni Wú Nípa Ọkùnrin Onígboyà Kan
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Gbára Lé Jèhófà Tó O Bá Ní Ẹ̀dùn Ọkàn
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
mwb22 March ojú ìwé 12
Dáfídì àti ọ̀kan lára àwọn ọmọ ogun rẹ̀ fara pa mọ́ sínú ihò kan bí Ọba Sọ́ọ̀lù ṣe ń rìn jáde. Ọmọ ogun náà mú idà lọ́wọ́, Dáfídì sì sọ fún un pé kó má pa Sọ́ọ̀lù.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Fi Sùúrù Dúró De Jèhófà

Dáfídì láǹfààní láti fòpin sí ìṣòro ẹ̀ (1Sa 24:3-5)

Dáfídì kó ara ẹ̀ níjàánu torí pé ojú tí Jèhófà fi ń wo nǹkan ló fi wo ọ̀rọ̀ náà (1Sa 24:6, 7)

Dáfídì nígbàgbọ́ pé Jèhófà máa yanjú ìṣòro òun (1Sa 24:12, 15; w04 4/1 16 ¶8)

Bíi ti Dáfídì, ó yẹ káwa náà fi sùúrù dúró de Jèhófà dípò ká máa wá ọ̀nà tí ò bá Ìwé Mímọ́ mu láti yanjú àwọn ìṣòro wa.​—Jem 1:4; w04 6/1 22-23.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́