ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb22 May ojú ìwé 10
  • Má Ṣe Gba Èròkerò Láyè

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Má Ṣe Gba Èròkerò Láyè
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ohun Tó Ń Fa Ẹ̀ṣẹ̀ àti Ikú
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
  • “Ẹ Para Dà Nípa Yíyí Èrò Inú Yín Pa Dà”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2023
  • Ǹjẹ́ O Rántí?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2019
  • Ǹjẹ́ O Rántí?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2021
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
mwb22 May ojú ìwé 10
Dáfídì ń wo Bátí-ṣébà látorí òrùlé rẹ̀.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Má Ṣe Gba Èròkerò Láyè

Dáfídì gba èròkerò láyè nínú ọkàn rẹ̀ (2Sa 11:2-4; w21.06 17 ¶10)

Dáfídì lo agbára àti ọlá àṣẹ tó ní láti bo ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ mọ́lẹ̀ (2Sa 11:5, 14, 15; w19.09 17 ¶15)

Dáfídì jìyà ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ (2Sa 12:9-12; w18.06 17 ¶7)

Tá ò bá fẹ́ máa wo ìwòkuwò, tá ò sì fẹ́ kí èròkerò gbà wá lọ́kàn, a gbọ́dọ̀ máa kó ara wa níjàánu. (Ga 5:16, 22, 23) Jèhófà lè ràn wá lọ́wọ́ láti gbé èròkerò kúrò lọ́kàn wa.

BI ARA RẸ PÉ, ‘Irú àwọn èrò wo ló sábà máa ń wá sí mi lọ́kàn tó yẹ kí n ṣiṣẹ́ lé?’

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́