ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb22 July ojú ìwé 4
  • Ọlọ́run Onídàájọ́ Òdodo Ni Jèhófà

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ọlọ́run Onídàájọ́ Òdodo Ni Jèhófà
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ìgbéraga Mú Kí Ábúsálómù Ṣọ̀tẹ̀
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Ámínónì Mọ Tara Ẹ̀ Nìkan, Ìyẹn sì Yọrí sí Àdánù Ńlá
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Kí Lo Máa Yááfì fún Jèhófà?
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Gbára Lé Jèhófà fún Ìrànlọ́wọ́
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
mwb22 July ojú ìwé 4

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Ọlọ́run Onídàájọ́ Òdodo Ni Jèhófà

Jèhófà ò gbàgbé ìwà ìkà tí Sọ́ọ̀lù hù sáwọn ará Gíbíónì (2Sa 21:1, 2)

Fàdákà àti wúrà ò lè mú ẹ̀bi ẹ̀jẹ̀ tó wà lórí Sọ́ọ̀lù àti agbo ilé rẹ̀ kúrò (Nọ 35:31, 33; 2Sa 21:3, 4)

Wọ́n pa méje lára àwọn ọmọ Sọ́ọ̀lù kí wọ́n lè mú ẹ̀bi ẹ̀jẹ̀ náà kúrò (2Sa 21:5, 6; it-1 932 ¶1)

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tí ọjọ́ orí wọn, ìlú ìbílẹ̀ àti àṣà wọn yàtọ̀ síra tí wọ́n ti fara da inínibíni, tí wọ́n sì ti jù sẹ́wọ̀n.

Báwo ni Róòmù 12:19-21 ṣe lè ràn wá lọ́wọ́ nígbà táwọn míì bá hùwà àìdáa sí wa?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́