ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb22 July ojú ìwé 9
  • Sapá Kó O Lè Lọ sí Ilé Ẹ̀kọ́ Àwọn Ajíhìnrere

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Sapá Kó O Lè Lọ sí Ilé Ẹ̀kọ́ Àwọn Ajíhìnrere
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Àwọn Ilé Tó Ń Fògo fún Olùkọ́ Wa Atóbilọ́lá
    Bá A Ṣe Ń Ná Owó Tẹ́ Ẹ Fi Ń Ṣètọrẹ
  • Ṣé Wàá Fẹ́ Lọ Sí Ilé Ẹ̀kọ́ Àwọn Ajíhìnrere?
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
  • Ẹ̀kọ́ Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Ni Kó O Máa Lé
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
  • “Ṣe Iṣẹ́ Ajíhìnrere”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2004
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
mwb22 July ojú ìwé 9

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI | OHUN TÓ O LÈ FI ṢE ÀFOJÚSÙN NÍ ỌDÚN IṢẸ́ ÌSÌN TÓ Ń BỌ̀

Sapá Kó O Lè Lọ sí Ilé Ẹ̀kọ́ Àwọn Ajíhìnrere

Kò dìgbà tí gbogbo nǹkan bá ń lọ geerege nígbèésí ayé rẹ kó o tó lè fi Ilé Ẹ̀kọ́ Àwọn Ajíhìnrere (SKE) ṣe àfojúsùn rẹ. Ohun tó ṣe pàtàkì jù ni pé kó o ní àjọṣe tó dáa pẹ̀lú Jèhófà, kó o sì múra tán láti lọ sìn níbikíbi tí ètò Ọlọ́run bá rán ẹ lọ.​—Ais 6:8.

Ẹ WO FÍDÍÒ NÁÀ JẸ́ KÍ ÌGBÀGBỌ́ MÚ KÓ O ṢE PÚPỌ̀ SÍ I​—SAPÁ KÓ O LÈ LỌ SÍ ILÉ Ẹ̀KỌ́ ÀWỌN AJÍHÌNRERE, KẸ́ Ẹ SÌ DÁHÙN ÀWỌN ÌBÉÈRÈ YÌÍ:

  • Àwòrán kan látinú fídíò “Jẹ́ Kí Ìgbàgbọ́ Mú Kó O Ṣe Púpọ̀ Sí I​—Sapá Kó O Lè Lọ Sí Ilé Ẹ̀kọ́ Àwọn Ajíhìnrere.” Gabriel ń ronú nípa bí Jèhófà ṣe ń bù kún un.

    Kí ló mú kí Gabriel máa ṣiyèméjì lórí bóyá kóun lọ sílé ẹ̀kọ́ náà tàbí kóun má lọ, báwo sì ni Fílípì 4:13 ṣe ràn án lọ́wọ́?

Tó bá wù ẹ́ láti lọ sí Ilé Ẹ̀kọ́ Àwọn Ajíhìnrere, sọ fún àwọn alàgbà ìjọ ẹ. Wọ́n á ṣàlàyé àwọn nǹkan tó o ní láti ṣe kó o lè kúnjú ìwọ̀n fún ilé ẹ̀kọ́ náà.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́