ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb22 November ojú ìwé 14
  • Àdúrà Mú Kí Jèhófà Gbé Ìgbésẹ̀

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àdúrà Mú Kí Jèhófà Gbé Ìgbésẹ̀
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • “Gbé Ọmọ Rẹ”
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Ó Fún Wa Lómìnira Láti Ṣe Ohun Tó Wù Wá
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2010
  • Ọba Kan Jẹ Èrè Ìgbàgbọ́ Rẹ̀
    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà—Ìmọ́lẹ̀ fún Gbogbo Aráyé, Apá Kìíní
  • ‘Ó Ń Bá A Nìṣó Ní Fífà Mọ́ Jèhófà’
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2012
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
mwb22 November ojú ìwé 14
Ọba Hẹsikáyà ń ṣàìsàn, ó sì ń gbàdúrà sí Jèhófà lórí ibùsùn rẹ̀.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Àdúrà Mú Kí Jèhófà Gbé Ìgbésẹ̀

Jèhófà sọ fún Hẹsikáyà pé àìsàn tó ń ṣe é ló máa pa á (2Ọb 20:1; ip-1 394 ¶23)

Hẹsikáyà bẹ Jèhófà pé kó rántí bóun ṣe fòótọ́ ọkàn sìn ín (2Ọb 20:2, 3; w17.03 21 ¶16)

Àdúrà Hẹsikáyà mú kí Jèhófà ràn án lọ́wọ́ (2Ọb 20:4-6; g01 8/8 14 ¶4)

Àdúrà wa lè mú kí Jèhófà ṣe ohun tí kò ní lọ́kàn láti ṣe. Báwo ni ìtàn yìí ṣe jẹ́ kó o rí i pé kò yẹ kó o fọ̀rọ̀ àdúrà ṣeré?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́