ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb23 January ojú ìwé 2
  • Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Jẹ́ Onírẹ̀lẹ̀?

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Jẹ́ Onírẹ̀lẹ̀?
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Jòsáyà Ní Àwọn Ọ̀rẹ́ Rere
    Kọ́ Ọmọ Rẹ
  • Kí La Rí Kọ́ Látinú Orin Tí Dáfídì Pè Ní “Ọrun”?
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Jòsáyà Pinnu Láti Ṣohun Tó Tọ́
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2009
  • Jòsáyà Fẹ́ràn Òfin Ọlọ́run
    Àwọn Ẹ̀kọ́ Tó O Lè Kọ́ Látinú Bíbélì
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
mwb23 January ojú ìwé 2
Ọba Jòsáyà ń tẹ́tí sílẹ̀ bí Ṣáfánì akọ̀wé rẹ̀ ṣe ń ka ohun tó wà nínú àkájọ ìwé fún un.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Jẹ́ Onírẹ̀lẹ̀?

Ó wu Jòsáyà gan-an láti ṣe ohun tó tọ́ lójú Jèhófà (2Ọb 22:1-5)

Ó gbà pé àwọn ṣàṣìṣe torí pé ó nírẹ̀lẹ̀ (2Ọb 22:13; w00 9/15 29-30)

Jèhófà bù kún Jòsáyà torí ó rẹ ara ẹ̀ sílẹ̀ (2Ọb 22:18-20; w00 9/15 30 ¶2)

Tá a bá gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà, tá a nírẹ̀lẹ̀, tá a gba ẹ̀bi wa lẹ́bi, tá a sì ṣe àtúnṣe tó yẹ, Jèhófà máa fi ojúure wò wá.​—Jem 4:6.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́