ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb23 January ojú ìwé 8
  • Jèhófà Máa Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́ Kó O Lè Ṣàṣeyọrí Lẹ́nu Iṣẹ́ Tó Le Gan-an

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Jèhófà Máa Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́ Kó O Lè Ṣàṣeyọrí Lẹ́nu Iṣẹ́ Tó Le Gan-an
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ǹjẹ́ O Lè Ṣe Bíi Ti Fíníhásì Bó O Bá Dojú Kọ Àwọn Ipò Tó Nira?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2011
  • Ìmọ̀ràn Onífẹ̀ẹ́ Tí Bàbá Kan Fún Ọmọ Ẹ̀
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Máa Ṣe Ohun Tí Jèhófà Fẹ́ Nígbà Gbogbo
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Ran Àwọn Ọ̀dọ́ Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Ṣàṣeyọrí
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
mwb23 January ojú ìwé 8

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Jèhófà Máa Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́ Kó O Lè Ṣàṣeyọrí Lẹ́nu Iṣẹ́ Tó Le Gan-an

Iṣẹ́ pàtàkì ni iṣẹ́ aṣọ́bodè tí àwọn ọmọ Léfì ń ṣe (1Kr 9:26, 27; w05 10/1 9 ¶8)

Fíníhásì ni olórí àwọn aṣọ́bodè àgọ́ ìjọsìn nígbà ayé Mósè (1Kr 9:17-20a)

Jèhófà ran Fíníhásì lọ́wọ́ kó lè ṣàṣeyọrí lẹ́nu iṣẹ́ rẹ̀ (1Kr 9:20b; w11 9/15 32 ¶7)

Àwòrán: 1. Arábìnrin kan tó jẹ́ ọ̀dọ́ ń wa katakata níbi iṣẹ́ ìkọ́lé. 2. Tọkọtaya kan tó jẹ́ àgbàlagbà ń wàásù látorí fóònù. 3. Tọkọtaya kan ń wàásù níbi tí àìní wà.

Ọ̀pọ̀ iṣẹ́ pàtàkì ni Jèhófà fún àwa náà láti ṣe. Tó bá ń ṣe ẹ́ bíi pé o ò mọ bó o ṣe máa ṣe iṣẹ́ kan, gbàdúrà sí Jèhófà kó o sì sọ fún Kristẹni kan tí òtítọ́ jinlẹ̀ nínú ẹ̀ pé kó ràn ẹ́ lọ́wọ́. —Flp 2:13.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́