ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb23 January ojú ìwé 14
  • Ran Àwọn Ọ̀dọ́ Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Ṣàṣeyọrí

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ran Àwọn Ọ̀dọ́ Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Ṣàṣeyọrí
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Mọ̀wọ̀n Ara Rẹ Bíi Ti Ẹ́sítà
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Ǹjẹ́ O Rántí?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2018
  • “Gbé Ọmọ Rẹ”
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Ìmọ̀ràn Onífẹ̀ẹ́ Tí Bàbá Kan Fún Ọmọ Ẹ̀
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
mwb23 January ojú ìwé 14
Ọba Dáfídì ń fi àwọn tó ń ṣiṣẹ́ lórí àwọn ohun tí wọ́n fẹ́ fi kọ́ tẹ́ńpìlì han Sólómọ́nì.

Dáfídì ṣètò àwọn òṣìṣẹ́ àtàwọn ohun èlò tí Sólómọ́nì máa fi kọ́ tẹ́ńpìlì

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Ran Àwọn Ọ̀dọ́ Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Ṣàṣeyọrí

Ó dá Dáfídì lójú pé Jèhófà máa ran Sólómọ́nì lọ́wọ́ láti kọ́ tẹ́ńpìlì náà parí (1Kr 22:5; w17.01 29 ¶8)

Dáfídì gba Sólómọ́nì níyànjú pé kó gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà, kó sì máa báṣẹ́ lọ (1Kr 22:11-13)

Dáfídì ṣe gbogbo ohun tó lè ṣe láti pèsè ohun tí Sólómọ́nì nílò fún iṣẹ́ náà (1Kr 22:14-16; w17.01 29 ¶7; wo àwòrán iwájú ìwé)

Àwòrán: 1. Alàgbà kan ń kọ́ arákùnrin kan tó jẹ́ ọ̀dọ́ nípa bó ṣe máa bójú tó ìpínlẹ̀ ìwàásù ìjọ wọn. Alàgbà náà fi àwòrán ìpínlẹ̀ ìwàásù hàn án, títí kan fọ́ọ̀mù tí wọ́n fi ń ṣàkọsílẹ̀ àwọn agbègbè tí wọ́n ti ṣe àti káàdì ìpínlẹ̀ kọ̀ọ̀kan. 2. Arákùnrin tó jẹ́ ọ̀dọ́ náà ń ṣàlàyé fún arákùnrin míì nípa bó ṣe máa lo káàdì ìpínlẹ̀ ìwàásù kan.

BI ARA Ẹ PÉ, ‘Báwo ni mo ṣe lè ran àwọn ọ̀dọ́ tó wà nínú ìjọ mi lọ́wọ́ kí wọ́n lè ṣàṣeyọrí, kí wọ́n sì láyọ̀ bí wọ́n ṣe ń sin Jèhófà?’—w18.03 11-12 ¶14-15.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́