ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb23 March ojú ìwé 5
  • Ọba Sólómọ́nì Ṣe Ìpinnu Tí Ò Mọ́gbọ́n Dání

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ọba Sólómọ́nì Ṣe Ìpinnu Tí Ò Mọ́gbọ́n Dání
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Sólómọ́nì Fọgbọ́n Ṣàkóso
    Kí Ló Wà Nínú Bíbélì?
  • Ṣé Àpẹẹrẹ Rere Ló Jẹ́ Fún ẹ Àbí Àpẹẹrẹ Búburú?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2011
  • Máa Fún Àwọn Míì Níṣìírí Nígbà Ìṣòro
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • “Ẹ Ní Ìgbàgbọ́ Nínú Jèhófà Ọlọ́run Yín”
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
mwb23 March ojú ìwé 5
Ọba Sólómọ́nì ń ronú lórí ohun kan tó fẹ́ ṣe. Àwòrán: 1. Ìlú kan tó ní odi gìrìwò. 2. Ẹṣin àti kẹ̀kẹ́ ẹṣin. 3. Ọkùnrin méjì ń ṣiṣẹ́ kára bí wọ́n ṣe ń kọ́ ògiri kan.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Ọba Sólómọ́nì Ṣe Ìpinnu Tí Ò Mọ́gbọ́n Dání

[Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Kíróníkà Kejì.]

Sólómọ́nì ń kó kẹ̀kẹ́ ẹṣin àti ẹṣin jọ fún ara rẹ̀ láti Íjíbítì (Di 17:15, 16; 2Kr 1:14, 17)

Sólómọ́nì nílò ọ̀pọ̀ èèyàn àti ìlú láti bójú tó àwọn ẹṣin àtàwọn kẹ̀kẹ́ ẹṣin ogun rẹ̀ (2Kr 1:14; it-1 174 ¶5; 427)

Nǹkan lọ dáadáa fáwọn èèyàn nígbà tí Sólómọ́nì kọ́kọ́ bẹ̀rẹ̀ sí í ṣàkóso. Àmọ́ nígbà tó ya, ó mú kí nǹkan nira fún wọn. Nígbà tí Rèhóbóámù ọmọ rẹ̀ di ọba, ó túbọ̀ mú kí nǹkan nira fáwọn èèyàn náà, ìyẹn sì mú kí wọ́n kẹ̀yìn sí i. (2Kr 10:3, 4, 14, 16) Gbogbo ìpinnu tá a bá ṣe ló máa ní àbájáde.​—Ga 6:7.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́