ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb23 March ojú ìwé 7
  • “Dáàbò Bo Ọkàn Rẹ”

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • “Dáàbò Bo Ọkàn Rẹ”
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Máa Ṣe Àwọn Ìpinnu Tó Fi Hàn Pé O Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Máa Ka Bíbélì Lójoojúmọ́ Kó O Lè Jẹ́ Ọlọ́gbọ́n
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Máa Ṣàkọsílẹ̀ Ìtẹ̀síwájú Rẹ
    Tẹra Mọ́ Kíkàwé Àti Kíkọ́ni
  • Kí La Kọ́ Nínú Ohun Táwọn Ọkùnrin Olóòótọ́ Sọ Kí Wọ́n Tó Kú?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2024
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
mwb23 March ojú ìwé 7

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

“Dáàbò Bo Ọkàn Rẹ”

Jèhófà mí sí Sólómọ́nì láti sọ pé: “Ju gbogbo ohun mìíràn tí ò ń dáàbò bò, dáàbò bo ọkàn rẹ.” (Owe 4:23) Ó bani nínú jẹ́ pé àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ò fi “gbogbo ọkàn wọn” bá Jèhófà Ọlọ́run wọn rìn. (2Kr 6:14) Kódà àwọn ìyàwó àjèjì tí Ọba Sólómọ́nì fẹ́ mú kí ọkàn rẹ̀ fà sí àwọn ọlọ́run míì. (1Ọb 11:4) Báwo lo ṣe lè dáàbò bo ọkàn rẹ? Ohun tá a jíròrò nìyẹn nínú Ilé Ìṣọ́ January 2019 ojú ìwé 14 sí 19.

Ẹ WO FÍDÍÒ NÁÀ ÀWỌN Ẹ̀KỌ́ LÁTINÚ ILÉ ÌṢỌ́​—DÁÀBÒ BO ỌKÀN RẸ, KẸ́ Ẹ SÌ DÁHÙN ÀWỌN ÌBÉÈRÈ YÌÍ:

Kí làwọn ohun tó fẹ́ ba ìgbàgbọ́ àwọn arákùnrin àtàwọn arábìnrin yìí jẹ́, báwo sì ni àpilẹ̀kọ tó wà fún ìkẹ́kọ̀ọ́ yìí ṣe ràn wọ́n lọ́wọ́ láti dáàbò bo ọkàn wọn?

  • Apá kan nínú fídíò “Àwọn Ẹ̀kọ́ Látinú Ilé Ìṣọ́​—Dáàbò Bo Ọkàn Rẹ.” Brent àti Lauren sọ ìrírí wọn.

    Brent àti Lauren

  • Apá kan nínú fídíò “Àwọn Ẹ̀kọ́ Látinú Ilé Ìṣọ́​—Dáàbò Bo Ọkàn Rẹ.” Umjay ń ṣèwádìí nípa àwọn tó ń ta ilé àti ilẹ̀.

    Umjay

  • Apá kan nínú fídíò “Àwọn Ẹ̀kọ́ Látinú Ilé Ìṣọ́​—Dáàbò Bo Ọkàn Rẹ.” Happy sọ ìrírí rẹ̀.

    Happy Layou

Báwo ni àpilẹ̀kọ náà ṣe ràn ẹ́ lọ́wọ́?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́