ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb23 May ojú ìwé 2
  • Máa Fi Ojú Tí Jèhófà Fi Ń Wo Àwọn Èèyàn Wò Wọ́n

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Máa Fi Ojú Tí Jèhófà Fi Ń Wo Àwọn Èèyàn Wò Wọ́n
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • “Ẹ Ní Ìgbàgbọ́ Nínú Jèhófà Ọlọ́run Yín”
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Jèhóṣáfátì Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà
    Ìwé Ìtàn Bíbélì
  • Jèhófà Gbèjà Jèhóṣáfátì
    Àwọn Ẹ̀kọ́ Tó O Lè Kọ́ Látinú Bíbélì
  • Ṣé Wàá Fọkàn sí Àwọn Ohun Tá A Ti Kọ Sílẹ̀?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2017
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
mwb23 May ojú ìwé 2

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Máa Fi Ojú Tí Jèhófà Fi Ń Wo Àwọn Èèyàn Wò Wọ́n

Ọba Jèhóṣáfátì hùwà òmùgọ̀ bó ṣe bá Ọba Áhábù da nǹkan pọ̀ (2Kr 18:1-3; w17.03 24 ¶7)

Jèhófà rán Jéhù pé kó lọ bá Jèhóṣáfátì wí (2Kr 19:1, 2)

Jèhófà ò gbàgbé gbogbo àwọn ohun rere tí Jèhóṣáfátì ṣe (2Kr 19:3; w15 8/15 11-12 ¶8-9)

Inú ń bí arákùnrin kan bó ṣe ń wo arákùnrin míì tó ń bá bàbá kan àti ọmọ ẹ̀ sọ̀rọ̀ dípò kó máa tún Gbọ̀ngàn Ìjọba ṣe.

BI ARA RẸ PÉ, ‘Ṣé mo lè fara wé Jèhófà ní ti pé kí n máa wo ibi tí àwọn arákùnrin àtàwọn arábìnrin mi dáa sí, dípò kí n gbájú mọ́ àṣìṣe wọn?’

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́