ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb23 May ojú ìwé 6
  • Jèhófà Máa Ń San Àwọn Tó Bá Nígboyà Lẹ́san

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Jèhófà Máa Ń San Àwọn Tó Bá Nígboyà Lẹ́san
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Bẹ̀rù Jèhófà?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2023
  • Jèhóádà Nígboyà
    Àwọn Ẹ̀kọ́ Tó O Lè Kọ́ Látinú Bíbélì
  • Ẹgbẹ́ Búburú Ò Jẹ́ Kí Jèhóáṣì Sin Jèhófà Mọ́
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2009
  • Kò Nira Jù Láti Sin Jèhófà
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
mwb23 May ojú ìwé 6
Àwòrán: 1. Jèhóádà àti Jèhóṣábéátì gbé Jèhóáṣì tó jẹ́ ọmọ ọwọ́ pa mọ́. 2. Jèhóádà Àlùfáà Àgbà fi Jèhóáṣì tó jẹ́ ọ̀dọ́ jọba.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Jèhófà Máa Ń San Àwọn Tó Bá Nígboyà Lẹ́san

Jèhóṣábéátì àti ọkọ ẹ̀ Jèhóádà gbé Jèhóáṣì pa mọ́ kí Ataláyà má baà pa á (2Kr 22:11, 12; w09 4/1 24 ¶1-2)

Jèhóádà gbé ìgbésẹ̀ akin, ó sì sọ Jèhóáṣì di ọba (2Kr 23:1-11, 14, 15; w09 4/1 24 ¶3-5)

Nítorí pé Jèhóádà nígboyà, ó sì ṣe ohun tó tọ́, wọ́n sin ín síbi tí wọ́n ń sin àwọn ọba sí (2Kr 24:15, 16; it-1 379 ¶5)

RONÚ LÓRÍ ÌBÉÈRÈ YÌÍ: Àwọn apá wo nínú ìjọsìn mi ni mo ti lè fi hàn pé mo nígboyà?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́