ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
Kò Nira Jù Láti Sin Jèhófà
Kò nira jù láti kẹ́kọ̀ọ́ nípa Jèhófà, ká sì ṣe ohun tó fẹ́ (Di 30:11-14; w09 11/1 31 ¶2)
Jèhófà ti fún ẹnì kọ̀ọ̀kan wa lómìnira láti yan ohun tó fẹ́ (Di 30:15; w09 11/1 31 ¶1)
Jèhófà fẹ́ ká yan ìyè (Di 30:19; w09 11/1 31 ¶4)
Kò ní nira jù fún wa láti sin Jèhófà, tá a bá ń tẹ̀ lé ìtọ́ni ẹ̀, tá a sì gbára lé e láti fún wa lókun.