ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 May ojú ìwé 15
  • “Kí Ni Jèhófà Ọlọ́run Rẹ Fẹ́ Kó O Ṣe?”

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • “Kí Ni Jèhófà Ọlọ́run Rẹ Fẹ́ Kó O Ṣe?”
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Kò Nira Jù Láti Sin Jèhófà
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Òótọ́ Làwọn Ìtàn Bíbélì, Kì Í Ṣe Àròsọ
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Ohun Tí Àpèjúwe Tó Wà Nínú Orin Onímìísí Kan Kọ́ Wa
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Ṣé O Ní Orúkọ Rere Bíi Ti Jóòbù?
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 May ojú ìwé 15

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

‘Kí Ni Jèhófà Ọlọ́run Rẹ Fẹ́ Kó O Ṣe?’

Máa ṣe ohun tí Jèhófà fẹ́ torí pé o bẹ̀rù rẹ̀, o sì nífẹ̀ẹ́ rẹ̀ (Di 10:12; w09 10/1 10 ¶3-4)

Ọ̀pọ̀ ìbùkún la máa rí tá a bá ń ṣe ohun tí Jèhófà fẹ́ (Di 10:13; w09 10/1 10 ¶6)

Jèhófà fẹ́ ká sún mọ́ òun (Di 10:15; cl 16 ¶2)

Jèhófà ò fipá mú wa láti ṣe ohun tó fẹ́. Kàkà bẹ́ẹ̀, ó fẹ́ ká nífẹ̀ẹ́ òun, ká sì máa ṣègbọràn sí òun “látọkàn wá.” (Ro 6:17) Tá a bá pinnu láti sin Jèhófà, àá gbádùn ìgbésí ayé tó nítumọ̀.

Àwòrán: Obìnrin kan pinnu láti sin Jèhófà. 1. Ó máa ń mutí, ó sì ń fa sìgá. 2. Ohun tó kọ́ nígbà tí wọ́n ń kọ́ o lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì wọ̀ ọ́ lọ́kàn gan-an. 3. Inú ẹ̀ ń dùn bí òun àtàwọn ọ̀rẹ́ ẹ̀ tí wọ́n jọ ń sin Jèhófà ṣe ń sọ̀rọ̀.
    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́