ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb23 November ojú ìwé 12
  • Ṣé O Ní Orúkọ Rere Bíi Ti Jóòbù?

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ṣé O Ní Orúkọ Rere Bíi Ti Jóòbù?
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • “Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2022
  • Jóòbù Gbé Orúkọ Jèhófà Ga
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2009
  • Ọkùnrin Àwòfiṣàpẹẹrẹ Kan Tó Tẹ́wọ́ Gba Ìbáwí
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2000
  • “Mi Ò Ní Fi Ìwà Títọ́ Mi Sílẹ̀!”
    Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Ìgbàgbọ́ Wọn
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
mwb23 November ojú ìwé 12
Jóòbù ń gbé oúnjẹ fún obìnrin kan tó jẹ́ aláìní àti ọmọ ẹ̀ ní ẹnubodè ìlú.

Jóòbù ń ṣàánú àwọn aláìní

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Ṣé O Ní Orúkọ Rere Bíi Ti Jóòbù?

Àwọn aládùúgbò Jóòbù máa ń bọ̀wọ̀ fún un (Job 29:​7-11)

Gbogbo èèyàn ló mọ̀ pé Jóòbù máa ń ṣàánú àwọn aláìní (Job 29:​12, 13; w02 5/15 22 ¶19; wo àwòrán iwájú ìwé)

Jóòbù jẹ́ olódodo, kì í sì í ṣojúsàájú (Job 29:14; it-1 655 ¶10)

Àwòrán: Ọ̀dọ́bìnrin kan ń ran àwọn mí ì lọ́wọ́. 1. Arábìnrin àgbàlagbà kan fọwọ́ kọ́ ọ ní ọwọ́ bí wọ́n ṣe jọ ń rìn. 2. Ó ń fara balẹ̀ tẹ́tí sí arábìnrin kan tó ń sọ ohun tó wà lọ́kàn ẹ̀. 3. Òun àti arábìnrin míì ń wàásù fún obìnrin kan tó mú ajá dání. 4. Ó ń gbé oúnjẹ fáwọn àlejò tó wá kí i nílé.

Orúkọ rere ṣe pàtàkì. (w09 2/1 15 ¶3-4) Tá a bá ń ṣe ohun tó tọ́ ní gbogbo ìgbà, ṣe là ń ṣe orúkọ rere fún ara wa.

BI ARA RẸ PÉ, ‘Irú èèyàn wo làwọn èèyàn mọ̀ mí sí?’

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́