Mósè ń kọ́ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ní orin tí wọ́n á fi máa bọlá fún Jèhófà
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
Ohun Tí Àpèjúwe Tó Wà Nínú Orin Onímìísí Kan Kọ́ Wa
A lè jẹ́ kí ohun tá à ń kọ́ àwọn èèyàn dà bí òjò winniwinni (Di 32:2, 3; w20.06 10 ¶8-9; wo àwòrán iwájú ìwé)
Jèhófà ni Àpáta náà (Di 32:4; w09 5/1 14 ¶3)
Jèhófà máa ń dáàbò bo àwọn èèyàn rẹ̀ bí ẹyẹ idì ṣe ń dáàbò bo àwọn ọmọ rẹ̀ (Di 32:11, 12; w01 10/1 9 ¶7)
Ibo la ti lè rí àpèjúwe tó dáa tá a lè lò tá a bá ń kọ́ àwọn èèyàn lẹ́kọ̀ọ́?