ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb23 May ojú ìwé 15
  • Jẹ́ Kó Máa Yá Ẹ Lára Láti Bá Àwọn Èèyàn Sọ̀rọ̀

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Jẹ́ Kó Máa Yá Ẹ Lára Láti Bá Àwọn Èèyàn Sọ̀rọ̀
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Máa Ṣe Àwọn Ìpinnu Tó Fi Hàn Pé O Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Tètè Ran Àwọn Tó Fẹ́ Kẹ́kọ̀ọ́ Òtítọ́ Lọ́wọ́
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2025
  • Máa Ṣàkọsílẹ̀ Ìtẹ̀síwájú Rẹ
    Tẹra Mọ́ Kíkàwé Àti Kíkọ́ni
  • Jẹ́ Onírẹ̀lẹ̀ Kó O sì Gbà Pé Àwọn Nǹkan Kan Wà Tó Ò Mọ̀
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2025
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
mwb23 May ojú ìwé 15

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Jẹ́ Kó Máa Yá Ẹ Lára Láti Bá Àwọn Èèyàn Sọ̀rọ̀

Ká sọ pé a pàdé ẹnì kan lọ́jà, nínú mọ́tò tàbí níbi tá a ti ń ṣiṣẹ́, lára ọ̀nà tó dáa jù tá a lè gbà wàásù fún ẹni náà ni pé ká kàn jọ máa sọ̀rọ̀. Àmọ́ tó bá jẹ́ pé bá a ṣe máa mú ìwàásù wọnú ìjíròrò náà ló gbà wá lọ́kàn, ìyẹn lè mú kí ẹ̀rù máa bà wá ká má sì mọ ohun tá a máa sọ. Dípò tí àá fi máa ronú ṣáá lórí bá a ṣe máa wàásù fún ẹni náà, ṣe ló yẹ ká jẹ́ kẹ́ni náà rí i pé a nífẹ̀ẹ́ òun àti pé ọ̀rọ̀ ẹ̀ jẹ wá lógún. (Mt 22:39; Flp 2:4) Tó bá wá ṣẹlẹ̀ pé àyè ṣí sílẹ̀ láti sọ ohun tá a gbà gbọ́ fún ẹni náà bá a ṣe jọ ń sọ̀rọ̀, ètò Ọlọ́run ti ṣe onírúurú nǹkan tó lè ràn wá lọ́wọ́.

Báwo la ṣe lè lo àwọn nǹkan tó wà nísàlẹ̀ yìí láti wàásù fún ẹnì kan tá a jọ ń sọ̀rọ̀?

Káàdì ìkànnì JW.ORG.
Àmì jw.org.
Àwòrán: Àwọn àṣàrò kúkúrú. 1. “Irú Ìwé Wo Ni Bíbélì?” 2. “Kí Ló Máa Ṣẹlẹ̀ Lọ́jọ́ Ọ̀la?” 3. “Kí Ló Lè Mú Kí Ìdílé Láyọ̀?” 4. “Ta Ló Ń Darí Ayé Yìí?” 5. “Ǹjẹ́ Ìyà Lè Dópin?” 6. “Ǹjẹ́ Àwọn Òkú Lè Jíǹde?” 7. “Kí Ni Ìjọba Ọlọ́run?” 8. “Ibo La Ti Lè Rí Ìdáhùn sí Àwọn Ìbéèrè Pàtàkì Nípa Ìgbésí Ayé?”

Ẹ WO FÍDÍÒ NÁÀ “IRIN Ń PỌ́N IRIN”​—BÍ A ṢE LÈ BÁ ÀWỌN ÈÈYÀN SỌ̀RỌ̀, KẸ́ Ẹ SÌ DÁHÙN ÌBÉÈRÈ YÌÍ:

Àwọn ohun mẹ́ta wo ló yẹ ká fi sọ́kàn tá a bá fẹ́ bẹ̀rẹ̀ ìjíròrò pẹ̀lú ẹni tá a pàdé?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́