ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb23 July ojú ìwé 6
  • “Lójú Ẹsẹ̀, Mo Gbàdúrà”

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • “Lójú Ẹsẹ̀, Mo Gbàdúrà”
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • “Máa Fi Ire Ṣẹ́gun Ibi”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2007
  • Nehemáyà Fi Ara Ẹ̀ Jìn Dípò Kó Jẹ Gàba
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • “Jọ̀wọ́, Ọlọ́run Mi, Rántí Mi fún Rere”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2011
  • Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Nehemáyà
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2006
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
mwb23 July ojú ìwé 6

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

“Lójú Ẹsẹ̀, Mo Gbàdúrà”

[Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Nehemáyà.]

Nehemáyà gbàdúrà kó tó dáhùn ìbéèrè tí ọba bi í (Ne 2:2-4; w08 2/15 3 ¶5)

Ọba ṣe ohun tí Nehemáyà béèrè lọ́wọ́ rẹ̀ (Ne 2:5, 6)

Tọ̀wọ̀tọ̀wọ̀ ni ọ̀dọ́kùnrin kan tó jẹ́ Ẹlẹ́rìí Jèhófà fi ṣàlàyé ohun tó jẹ́ ìgbàgbọ́ ẹ̀ fún olùkọ́ wọn ní kíláàsì. Wọ́n lẹ àwọn àmì aláwọ̀ mèremère tí wọ́n fi ń ṣagbátẹrù kí ọkùnrin máa fẹ́ ọkùnrin àti kí obìnrin máa fẹ́ obìnrin sára ògiri kíláàsì náà.

RONÚ LÓRÍ ÌBÉÈRÈ YÌÍ: Kí la lè ṣe tẹ́nì kan bá bi wá láìròtẹ́lẹ̀ pé ká ṣàlàyé ohun tá a gbà gbọ́?​—be 178 ¶1.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́