ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb23 September ojú ìwé 12
  • Ìfẹ́ Jèhófà Tí Kì í Yẹ̀ Ń Dáàbò Bò Wá Lọ́wọ́ Irọ́ Sátánì

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ìfẹ́ Jèhófà Tí Kì í Yẹ̀ Ń Dáàbò Bò Wá Lọ́wọ́ Irọ́ Sátánì
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Báwo Ni Ìfẹ́ Jèhófà Tí Kì Í Yẹ̀ Ṣe Ń Ṣe Ọ́ Láǹfààní?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2021
  • Kí Lo Lè Ṣe Láti Di Ọ̀rẹ́ Ọlọ́run?
    Kí Ni Bíbélì Kọ́ Wa?
  • Jóòbù Gbé Orúkọ Jèhófà Ga
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2009
  • Báwo La Ṣe Lè Fi Hàn Pé A Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà?
    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìjíròrò Látinú Bíbélì
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
mwb23 September ojú ìwé 12

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Ìfẹ́ Jèhófà Tí Kì í Yẹ̀ Ń Dáàbò Bò Wá Lọ́wọ́ Irọ́ Sátánì

Sátánì fẹ́ káwọn èèyàn gbà pé àmúwá Ọlọ́run làwọn nǹkan burúkú tó ń ṣẹlẹ̀ (Job 8:4)

Ó fẹ́ ká máa ronú pé kò sí àǹfààní kankan nínú kéèyàn jẹ́ olóòótọ́ torí pé ojú kan náà ni Jèhófà fi ń wo ẹni burúkú àti ẹni rere (Job 9:​20-22; w15 7/1 12 ¶3)

Ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ tí Jèhófà ní sí wa kò ní jẹ́ kí Sátánì fi irọ́ tàn wá jẹ, á sì jẹ́ ká lè jẹ́ olóòótọ́ sí Jèhófà (Job 10:12; Sm 32:​7, 10; w21.11 6 ¶14)

Arábìnrin kan ń ronú lórí àwọn ọ̀nà tí Jèhófà ti gbà bù kún è, ó sì ń kọ́ ọ sílẹ̀. Tọkọtaya kan gbé oúnjẹ wá fún un, arábìnrin mí ì gbá a mọ́ra nípàdé, ó sì ń wo ètò Tẹlifíṣọ̀n JW.

GBÌYÀNJÚ ÈYÍ WÒ: Tó o bá ń kojú àdánwò, ronú nípa àwọn ọ̀nà tí Jèhófà ti gbà fìfẹ́ tí kì í yẹ̀ hàn sí ẹ, kọ wọ́n sílẹ̀, kó o sì máa ṣàyẹ̀wò ẹ̀ látìgbàdégbà. Tó o bá ṣe bẹ́ẹ̀, ìyẹn ò ní jẹ́ kó o bọ́hùn.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́