ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb23 November ojú ìwé 15
  • Kí Nìdí Tí Wíwo Àwòrán Ìṣekúṣe Fi Burú?

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Kí Nìdí Tí Wíwo Àwòrán Ìṣekúṣe Fi Burú?
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Báwo Ni Mo Ṣe Lè Yẹra Fún Wíwo Àwòrán Oníhòòhò?
    Jí!—2008
  • Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Yẹra fún Wíwo Àwòrán Ìṣekúṣe?
    Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé
  • Kí Nìdí Tí Kò Fi Yẹ Kí N Máa Wo Àwòrán Oníhòòhò?
    Àwọn Ìbéèrè Tí Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè—Àwọn Ìdáhùn Tí Ó Gbéṣẹ́, Apá Kejì
  • Àwòrán Oníhòòhò​—Ó Léwu Àbí Kò Léwu?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2013
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
mwb23 November ojú ìwé 15

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Kí Nìdí Tí Wíwo Àwòrán Ìṣekúṣe Fi Burú?

Àwòrán ìṣekúṣe wọ́pọ̀ gán-an lóde òní, ó sì rọrùn láti rí. Ọ̀pọ̀ èèyàn ni ò rí ohun tó burú nínú ẹ̀, títí kan àwọn tó sọ pé àwọn ń sin Ọlọ́run.

Àwòrán: Àwọn apá kan nínú fídíò “Ṣé Ẹ̀ṣẹ̀ Ni Wíwo Àwòrán Ìṣekúṣe Jẹ́ Lójú Ọlọ́run?” 1. Àwọn ọkùnrin méjì àti obìnrin kan wo fóònù wọn níbi tí wọ́n ti ń dúró de ọkọ̀. Àwọn ọkùnrin méjèèjì náà ń wo ohun tí wọ́n pè ní “XXX.” 2. Nígbà tó yá, ọ̀kan lára àwọn ọkùnrin náà àtìyàwó ẹ̀ ń ka àpilẹ̀kọ náà “Ohun Tó Ń Mú Ọkàn Fà Sí Ìṣekúṣe?” lórí jw.org.

Ẹ WO FÍDÍÒ NÁÀ ṢÉ Ẹ̀ṢẸ̀ NI WÍWO ÀWÒRÁN ÌṢEKÚṢE JẸ́ LÓJÚ ỌLỌ́RUN? KẸ́ Ẹ SÌ DÁHÙN ÌBÉÈRÈ YÌÍ:

Báwo làwọn ẹsẹ Bíbélì yìí ṣe jẹ́ ká mọ bó ṣe máa ń rí lára Ọlọ́run tí ẹnì kan bá ń wo àwòrán ìṣekúṣe?

  • 1Kọ 6:​9, 10

  • Mt 5:28

  • Kol 3:5

  • Jem 1:​14, 15

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́