Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀
Kí ló yẹ kó o ṣe tó o bá fẹ́ kí ọjọ́ ọ̀la ẹ dáa? Tó o bá ka ìwé yìí, wàá rí oríṣiríṣi nǹkan táwọn èèyàn ń ṣe torí pé wọ́n fẹ́ kí ọjọ́ ọ̀la wọn dáa. Wàá tún rí ohun kan ṣoṣo tó lè mú kí ọjọ́ ọ̀la ẹ dáa.
Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.
Má bínú, fídíò yìí kò jáde.