ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • wp21 No. 3 ojú ìwé 16
  • Ohun Tó Lè Mú Kí Ọjọ́ Ọ̀la Rẹ Dáa

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ohun Tó Lè Mú Kí Ọjọ́ Ọ̀la Rẹ Dáa
  • Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde)—2021
  • Ìsọ̀rí
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • KÍ LÓ LÈ MÚ KÍ ỌJỌ́ Ọ̀LA RẸ DÁA?
  • Ìwé Mímọ́ sọ pé:
  • Gbogbo Èèyàn Ló Fẹ́ Kí Ọjọ́ Ọ̀la Wọn Dáa
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde)—2021
  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde)—2021
  • Wíwá Ìgbésí Ayé Aláàbò Kiri
    Jí!—1998
  • Ṣó Dájú Pé Ọjọ́ Ọ̀la Ẹnì Kan Á Dáa Tó Bá Ṣáà Ti Ń Hùwà Tó Dáa?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde)—2021
Àwọn Míì
Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde)—2021
wp21 No. 3 ojú ìwé 16
Obìnrin kan wà ní yàrá ìkàwé, ó ń ka Bíbélì látorí fóònù rẹ̀.

Ohun Tó Lè Mú Kí Ọjọ́ Ọ̀la Rẹ Dáa

KÍ LÓ LÈ MÚ KÍ ỌJỌ́ Ọ̀LA RẸ DÁA?

  • Ṣé tó o bá kàwé dáadáa ni?

  • Ṣé tó o bá lówó rẹpẹtẹ ni?

  • Ṣé tó o bá jẹ́ èèyàn dáadáa ni?

  • Àbí nǹkan míì?

Ìwé Mímọ́ sọ pé:

“Ọgbọ́n dára fún ọ. Tí o bá wá a rí, ọjọ́ ọ̀la rẹ á dára.”​—ÒWE 24:14.

Tó o bá ka Ìwé Mímọ́, wàá rí àwọn ọ̀rọ̀ ọgbọ́n tó lè jẹ́ kí ọjọ́ ọ̀la rẹ dáa.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́