ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • yb16 ojú ìwé 30
  • A Mú Bíbélì Ìtumọ̀ Ayé Tuntun Jáde Láwọn Èdè Míì

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • A Mú Bíbélì Ìtumọ̀ Ayé Tuntun Jáde Láwọn Èdè Míì
  • Ìwé Ọdọọdún Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà—2016
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Bibeli To Maa Lalope
    Ìwé Ọdọọdún Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà—2015
  • Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
    Jí!—2014
  • Gbogbo Àròpọ̀ ti Ọdún 2014
    Ìwé Ọdọọdún Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà—2015
  • Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
    Jí!—2014
Àwọn Míì
Ìwé Ọdọọdún Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà—2016
yb16 ojú ìwé 30

ÀWỌN OHUN PÀTÀKÌ TÓ ṢẸLẸ̀ LỌ́DÚN TÓ KỌJÁ

A Mú Bíbélì Ìtumọ̀ Ayé Tuntun Jáde Láwọn Èdè Míì

NÍGBÀ tó fi máa di August 31, 2015, a ti túmọ̀ Bíbélì Ìtumọ̀ Ayé Tuntun lápá kan tàbí lódindi sí èdè mọ́kàndínláàádóje [129]. Bíbélì yìí tún wà lórí Ìkànnì jw.org lédè mọ́kàndínláàádóje [129], méje lára wọn sì jẹ́ èdè àwọn adití. Àwọn tá a mú jáde lọ́dún iṣẹ́ ìsìn 2015 la tò sísàlẹ̀ yìí:

ỌJỌ́ TÓ JÁDE

ORÍLẸ̀-ÈDÈ

ÈDÈ

ÈYÍ TÓ JẸ́

September 5, 2014

Màléṣíà

Malay

Ìwé Mímọ́ lédè Gíríìkìa

September 6, 2014

South Korea

Korean

Ẹ̀dà Tá A Tún Ṣe

September 19, 2014

Jọ́jíà

Azerbaijani

Odindi Bíbélì

September 26, 2014

Kazakhstan

Kazakh

Odindi Bíbélì

October 10, 2014

Gánà

Ga

Ìwé Mímọ́ lédè Gíríìkìb

November 14, 2014

Philippines

Hiligaynon

Odindi Bíbélì

December 12, 2014

Nàìjíríà

Ísókó

Ìwé Mímọ́ lédè Gíríìkìc

December 13, 2014

Etiópíà

Amharic

Odindi Bíbélì

December 19, 2014

Fíjì

Fijian

Odindi Bíbélì

December 26, 2014

Mẹ́síkò

Tzotzil

Ìwé Mímọ́ lédè Gíríìkìd

December 29, 2014

Gánà

Ewe

Odindi Bíbélì

March 22, 2015

Brazil

Potogí

Ẹ̀dà Tá A Tún Ṣe

May 9, 2015

Sáńbíà

Luvale

Odindi Bíbélì

July 17, 2015

Haiti

Haitian Creole

Odindi Bíbélì

August 28, 2015

Kẹ́ńyà

Kikuyu

Ìwé Mímọ́ lédè Gíríìkìe

August 28, 2015

Kóńgò (Kinshasa)

Kóńgò

Odindi Bíbélì

a Èyí ni ìgbà àkọ́kọ́ tá a máa mú apá èyíkéyìí nínú Bíbélì Ìtumọ̀ Ayé Tuntun jáde ní èdè yìí.

b Èyí ni ìgbà àkọ́kọ́ tá a máa mú apá èyíkéyìí nínú Bíbélì Ìtumọ̀ Ayé Tuntun jáde ní èdè yìí.

c Èyí ni ìgbà àkọ́kọ́ tá a máa mú apá èyíkéyìí nínú Bíbélì Ìtumọ̀ Ayé Tuntun jáde ní èdè yìí.

d Èyí ni ìgbà àkọ́kọ́ tá a máa mú apá èyíkéyìí nínú Bíbélì Ìtumọ̀ Ayé Tuntun jáde ní èdè yìí.

e Èyí ni ìgbà àkọ́kọ́ tá a máa mú apá èyíkéyìí nínú Bíbélì Ìtumọ̀ Ayé Tuntun jáde ní èdè yìí.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́