Gbogbo Àròpọ̀ ti Ọdún 2014
Iye Ẹ̀ka Ọ́fíìsì Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà: 90
Iye Orílẹ̀-Èdè Tó Ròyìn: 239
Àròpọ̀ Iye Ìjọ: 115,416
Àwọn Tó Wá Síbi Ìrántí Ikú Kristi Kárí Ayé: 19,950,019
Àwọn Tó Jẹ Ohun Ìṣàpẹẹrẹ Kárí Ayé: 14,121
Góńgó Akéde: 8,201,545
Ìpíndọ́gba Akéde Tó Ń Wàásù Lóṣooṣù: 7,867,958
Iye Tá A Fi Pọ̀ Ju Ti Ọdún 2013: 169,581
Àròpọ̀ Iye Àwọn Tó Ṣèrìbọmi: 275,581
Ìpíndọ́gba Aṣáájú-Ọ̀nà Olùrànlọ́wọ́ Lóṣooṣù: 635,298
Ìpíndọ́gba Aṣáájú-Ọ̀nà Déédéé Lóṣooṣù: 1,089,446
Àròpọ̀ Wákàtí Tá A Lò Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìwàásù: 1,945,487,604
Ìpíndọ́gba Àwọn Tá À Ń Kọ́ Lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Lóṣooṣù: 9,499,933
Ní ọdún iṣẹ́ ìsìn 2014, ó ju igba ó lé mẹ́rìnlélógún [224] mílíọ̀nù owó dọ́là ti ilẹ̀ Amẹ́ríkà táwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ná láti bójú tó àwọn aṣáájú-ọ̀nà àkànṣe, àwọn míṣọ́nnárì àtàwọn alábòójútó arìnrìn-àjò lẹ́nu iṣẹ́ wọn.
Bákan náà, kárí ayé, iye àwọn tó ń ṣiṣẹ́ láwọn ẹ̀ka ọ́fíìsì wa jẹ́ ẹgbẹ̀rún mẹ́rìnlélógún, ọgọ́rùn-ún méje àti mọ́kànlá [24,711]. Wọ́n wà lára Àwọn Tó Ń Ṣe Àkànṣe Iṣẹ́ Ìsìn Alákòókò Kíkún Lára Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà.