ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • yb14 ojú ìwé 176-192
  • Gbogbo Àròpọ̀ ti Ọdún 2013

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Gbogbo Àròpọ̀ ti Ọdún 2013
  • Ìwé Ọdọọdún Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà—2014
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Gbogbo Àròpọ̀ ti Ọdún 2015
    Ìwé Ọdọọdún Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà—2016
  • Gbogbo Àròpọ̀ ti Ọdún 2014
    Ìwé Ọdọọdún Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà—2015
  • Gbogbo Àròpọ̀ ti Ọdún 2012
    Ìwé Ọdọọdún Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà—2013
  • Gbogbo Àròpọ̀ ti Ọdún 2016
    Ìwé Ọdọọdún Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà—2017
Àwọn Míì
Ìwé Ọdọọdún Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà—2014
yb14 ojú ìwé 176-192

Gbogbo Àròpọ̀ ti Ọdún 2013

  • Iye Ẹ̀ka Ọ́fíìsì Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà: 91

  • Iye Orílẹ̀-Èdè Tó Ròyìn: 239

  • Àròpọ̀ Iye Ìjọ: 113,823

  • Àwọn Tó Wá Síbi Ìrántí Ikú Kristi Kárí Ayé: 19,241,252

  • Àwọn Tó Jẹ Ohun Ìṣàpẹẹrẹ Kárí Ayé: 13,204

  • Góńgó Akéde: 7,965,954

  • Ìpíndọ́gba Akéde Tó Ń Wàásù Lóṣooṣù: 7,698,377

  • Iye Tá A Fi Pọ̀ Ju Ti Ọdún 2012: 159,383

  • Àròpọ̀ Iye Àwọn Tó Ṣèrìbọmi: 277,344

  • Ìpíndọ́gba Aṣáájú-Ọ̀nà Olùrànlọ́wọ́ Lóṣooṣù: 496,089

  • Ìpíndọ́gba Aṣáájú-Ọ̀nà Déédéé Lóṣooṣù: 1,025,677

  • Àròpọ̀ Wákàtí Tá A Lò Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìwàásù: 1,841,180,235

  • Ìpíndọ́gba Àwọn Tá À Ń Kọ́ Lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Lóṣooṣù: 9,254,963

Lọ́dún iṣẹ́ ìsìn 2013, àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ná nǹkan bí igba [200] mílíọ̀nù owó dọ́là ti ilẹ̀ Amẹ́ríkà láti bójú tó àwọn aṣáájú-ọ̀nà àkànṣe, àwọn míṣọ́nnárì àtàwọn alábòójútó arìnrìn-àjò lẹ́nu iṣẹ́ wọn.

Bákan náà, kárí ayé, iye àwọn tó ń ṣiṣẹ́ láwọn ẹ̀ka ọ́fíìsì wa jẹ́ ẹgbẹ̀rún méjìlélógún, ọgọ́rùn-ún méje àti mọ́kàndínlógún [22,719]. Wọ́n wà lára Àwọn Tó Ń Ṣe Àkànṣe Iṣẹ́ Ìsìn Alákòókò Kíkún Lára Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà.

[Graph tó wà ní ojú ìwé 177]

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́