ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mrt àpilẹ̀kọ 88
  • Ohun Tí Ìjọba Ọlọ́run Máa Ṣe sí Ogun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ohun Tí Ìjọba Ọlọ́run Máa Ṣe sí Ogun
  • Àkójọ Àpilẹ̀kọ àti Fídíò
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ta Ló Máa Gba Àwọn Aráàlú?—Kí Ni Bíbélì Sọ?
    Àkójọ Àpilẹ̀kọ àti Fídíò
  • Ó Ti Lé Lọ́dún Kan Tí Ogun Ti Ń Jà ní Ukraine—Kí Ni Bíbélì Sọ Pé Ọlọ́run Máa Ṣe?
    Àkójọ Àpilẹ̀kọ àti Fídíò
  • Nǹkan Ò Rọrùn Fáwọn Èèyàn Lọ́dún 2023—Kí Ni Bíbélì Sọ?
    Àkójọ Àpilẹ̀kọ àti Fídíò
  • Ìgbà Wo Ni Gbogbo Ogun Yìí Máa Dópin?
    Àkójọ Àpilẹ̀kọ àti Fídíò
Àwọn Míì
Àkójọ Àpilẹ̀kọ àti Fídíò
mrt àpilẹ̀kọ 88
Ọkùnrin kan ń ti kẹ̀kẹ́ ládùúgbò tí ogun ti jà tí ọ̀pọ̀ ọkọ̀ tí wọ́n fi ń jagun sì ti bà jẹ́.

Chris McGrath/Getty Images

Ohun Tí Ìjọba Ọlọ́run Máa Ṣe sí Ogun

Ogun tó ń jà kárí ayé ti ba ọ̀pọ̀ nǹkan jẹ́, ó sì ti fa ọ̀pọ̀ ìnira fáwọn èèyàn. Kíyè sí àwọn ìròyìn tó tẹ̀ lé e yìí:

  • “Iye àwọn tí ogun pa lórílẹ̀-èdè Etiópíà àti Ukraine lọ́dún tó kọjá nìkan ju àwọn tí ogun ti pa láti ọdún 1994.”—Peace Research Institute Oslo, June 7, 2023.

  • “Lọ́dún 2022, ogun tó jà ní Ukraine wà lára ogun tó tíì burú jù lọ. Kárí ayé ìwà ipá tó ń ṣẹlẹ̀ láàárín àwọn olóṣèlú légbá kan sí i lọ́dún tó kọjá, ọ̀kẹ́ àìmọye èèyàn lèyí sì ṣàkóbá fún.”—The Armed Conflict Location & Event Data Project (ACLED), February 8, 2023.

Bíbélì fi wá lọ́kàn balẹ̀. Ó sọ pé “Ọlọ́run ọ̀run máa gbé ìjọba kan kalẹ̀, tí kò ní pa run láé.” (Dáníẹ́lì 2:44) Lábẹ́ Ìjọba yìí, Ọlọ́run máa “fòpin sí ogun kárí ayé.”—Sáàmù 46:9.

Kí Ni Ìjọba Ọlọ́run?

“Ilé Ìṣọ́” tí àkòrí ẹ̀ jẹ́ “Kí Ni Ìjọba Ọlọ́run?”

A rọ̀ ẹ́ pé kó o ka Ilé Ìṣọ́ tí àkòrí ẹ̀ sọ pé “Kí Ni Ìjọba Ọlọ́run?” Wàá rí ìdáhùn sáwọn ìbéèrè bíi:

  • Ta Ni Ọba Ìjọba Ọlọ́run?

  • Ìgbà Wo Ni Ìjọba Ọlọ́run Máa Ṣàkóso Ayé?

  • Kí Ni Ìjọba Ọlọ́run Máa Ṣe?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́