ÀWỌN ÀWÒRÁN ÌTÀN BÍBÉLÌ
Àwọn Ọmọ Ísírẹ́lì Ṣe Ère Ọmọ Màlúù Oníwúrà
Kẹ́kọ̀ọ́ nípa Áárónì, ẹ̀gbọ́n Mósè àti bó ṣe dẹ́ṣẹ̀ nípa bíbá àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ṣe ère ọmọ màlúù oníwúrà kan. Ka àwòrán ìtàn Bíbélì tó wà lórí ìkànnì tàbí kó o tẹ̀ ẹ́ jáde.
Ka Ìtàn Bíbélì yìí lórí ìkànnì tàbí kó o ka èyí tó o wà jáde