Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kejì (yp2) Ara Èèpo Iwájú Ìwé Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Àkọlé Sí/Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Orúkọ Òǹṣèwé Sí Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí Ọ̀rọ̀ Rèé O Ẹ̀yin Òbí Ibo Ni Mo Ti Lè Rí Ìmọ̀ràn Tó Dáa Jù Lọ? Àlàyé Ọ̀rọ̀ Ọkùnrin Àti Obìnrin Ṣó Ti Yẹ Kí N Lẹ́ni Tí Mò Ń Fẹ́? Kí Ló Burú Nínú Fífẹ́ra Sọ́nà Ní Bòókẹ́lẹ́? Ṣé Ẹni Tó Yẹ Kí N Fẹ́ Nìyí? Àwòkọ́ṣe—Omidan Ará Ṣúnémù Ìgbà Wo Ló Dàṣejù? Kí Nìdí Tí Kò Fi Yẹ Kí N Ní Ìbálòpọ̀ Kí N Tó Ṣègbéyàwó? Àwòkọ́ṣe—Jósẹ́fù Ohun Tí Mo Rò—Ọ̀rọ̀ Ọkùnrin àti Obìnrin Ìyípadà Ara Kí Nìdí Tára Mi Fi Ń Yí Pa Dà? Bí Mi Ò Bá Fẹ́ràn Bí Mo Ṣe Rí Ńkọ́? Kí Nìdí Tí Mo Fi Ń Ṣàìsàn Tó Báyìí? Ohun Tí Mo Rò—Ìyípadà Ara Yíyan Ọ̀rẹ́ Kí Ni Mo Lè Ṣe Tí Mi Ò Fi Ní Máa Dá Wà? Kí Nìdí Táwọn Ọ̀rẹ́ Mi Fi Ń Ṣe Ohun Tó Ń Dùn Mí? Àwòkọ́ṣe—Lìdíà Kí Ló Burú Nínú Kéèyàn Máa Ṣọ̀rẹ́ Lórí Íńtánẹ́ẹ̀tì? Kí Ló Burú Nínú Kéèyàn Máa Sọ̀rọ̀ Ẹlòmíì Lẹ́yìn? Ohun Tí Mo Rò—Yíyan Ọ̀rẹ́ Iléèwé Àtàwọn Ojúgbà Rẹ Báwo Ni Mo Ṣe Lè Máa Ṣe Dáadáa Sí I Níléèwé? Báwo Ni Mo Ṣe Lè Dáàbò Bo Ara Mi Níléèwé? Báwo Ni Mi Ò Ṣe Ní Í Jẹ́ Káwọn Ojúgbà Mi Kó Ìwà Tí Ò Dáa Ràn Mí? Àwòkọ́ṣe—Àwọn Hébérù Mẹ́ta Ta Ló Yẹ Kí N Sọ Fún Bí Mo Bá Ń Yọ́ Ìwà Tí Kò Tọ́ Hù? Kí Ló Yẹ Kí N Mọ̀ Nípa Yíyan Ọ̀rẹ́ Níléèwé? Ohun Tí Mo Rò—Iléèwé Àtàwọn Ojúgbà Rẹ Ọ̀ràn Owó Báwo Ni Mo Ṣe Lè Lówó? Báwo Ni Mo Ṣe Lè Máa Ṣọ́ Owó Ná? Báwọn Òbí Mi Ò Bá Lówó Ńkọ́? Àwòkọ́ṣe—Opó Aláìní Ohun Tí Mo Rò—Ọ̀ràn Owó Àwọn Òbí Rẹ Kí Ni Mo Lè Ṣe Táwọn Òbí Mi Bá Ń Rí Sí Mi Ṣáá? Òfin Yìí Ò Wa Pọ̀ Jù! Bí Òbí Mi Bá Ń Mutí Lámujù Tó Sì Ń Lòògùn Olóró Ńkọ́? Àwòkọ́ṣe—Hesekáyà Kí Ni Kí N Ṣe Báwọn Òbí Mi Bá Ń Jà? Báwo Ni Mo Ṣe Lè Láyọ̀ Bí Òbí Mi Bá Jẹ́ Anìkàntọ́mọ? Ohun Tí Mo Rò—Àwọn Òbí Rẹ Bí Nǹkan Ṣe Ń rí Lára Ẹ Báwo Ni Mo Ṣe Lè Mú Ohun Tó Ń Ṣe Mí Mọ́ra? Kí Ló Mú Kí N Máa Rò Pé Mi Ò Gbọ́dọ̀ Ṣàṣìṣe? Àwòkọ́ṣe—Pọ́ọ̀lù Báwo Ni Mo Ṣe Lè Sá Fún Bíbá Ọkùnrin Tàbí Obìnrin Bíi Tèmi Lò Pọ̀? Báwo Ni Mo Ṣe Lè Gbọ́kàn Mi Kúrò Lórí Ìbálòpọ̀? Ohun Tí Mo Rò—Bí Nǹkan Ṣe Ń Rí Lára Ẹ Eré Ìtura Ṣó Yẹ Kí N Máa Ṣeré Orí Kọ̀ǹpútà? Báwo Ni Mi Ò Ṣe Ní Ki Àṣejù Bọ Orin Gbígbọ́? Àwòkọ́ṣe—Dáfídì Báwo Ni Mo Ṣe Lè Gbádùn Ara Mi? Kí Nìdí Tí Kò Fi Yẹ Kí N Máa Wo Àwòrán Oníhòòhò? Ohun Tí Mo Rò—Eré Ìtura Àjọṣe Rẹ Pẹ̀lú Ọlọ́run Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kí N Máa Fàwọn Ìlànà Bíbélì Ṣèwà Hù? Àwòkọ́ṣe—Ásáfù Báwo Ni Mo Ṣe Lè Di Ọ̀rẹ́ Ọlọ́run? Báwo Ni Mo Ṣe Lè Ṣàlàyé Ohun Tí Mo Gbà Gbọ́ Nípa Ọlọ́run? Ṣó Yẹ Kí N Ṣèrìbọmi? Kí Ni Màá Fayé Mi Ṣe? Ohun Tí Mo Rò—Àjọṣe Rẹ Pẹ̀lú Ọlọ́run Ibi Tí Mo Kọ Èrò Mi Sí Ara Èèpo Ẹ̀yìn Ìwé Èèpo Ẹ̀yìn Ìwé