April Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Ìròyìn Yìí “Ohun Tí O Jẹ́jẹ̀ẹ́, San Án” Àwọn Nǹkan Wo Ló Máa Lọ tí Ìjọba Ọlọ́run Bá Dé? ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ Mo Pinnu Pé Ọmọ Ogun Kristi Ni Màá Jẹ́ ‘Onídàájọ́ Ilẹ̀ Ayé’ Máa Ń Ṣe Ohun Tó Tọ́ Nígbà Gbogbo Ṣé Èrò Tí Jèhófà Ní Nípa Ìdájọ́ Òdodo Ni Ìwọ Náà Ní? Yọ̀ǹda Ara Rẹ Tinútinú, Kí Ìyìn Lè Jẹ́ ti Jèhófà!