August 8 Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí Èé Ṣe Tí Ọ̀pọ̀ Èèyàn Fi Nífẹ̀ẹ́ Sí Ìbẹ́mìílò? Ìdí Tó Fi Yẹ Kí O Yẹra Fún Ìbẹ́mìílò Èdè—Òun Ló Ń Ṣínà Ìjùmọ̀sọ̀rọ̀, Òun Náà Ló Ń Dènà Rẹ̀ Ǹjẹ́ Ó Yẹ Ká Máa Fi Ẹ̀dùn Ọkàn Hàn? Ǹjẹ́ O Mọ̀? Ìrèké—Àràbà Ni Láàárín Àwọn Koríko Ǹjẹ́ Ó Ti Tó Àkókò Láti Ní Bẹ́ẹ̀dì Tuntun? Ṣíṣe Ara Lọ́ṣọ̀ọ́—Ìdí Tí A Kò Fi Gbọ́dọ̀ Ṣàṣejù Báwo Ni Gbígbé Lókè Òkun Ṣe Lè Gbè Mí? Pátímọ́sì—Erékùṣù Àpókálíìsì Wíwo Ayé Wọ́n Gbé Òtítọ́ Pa Mọ́ fún Àádọ́ta Ọdún—Èé Ṣe? Títọ́ Àwọn Ọmọ Di Ẹni Tó Lẹ́kọ̀ọ́—Báwo La Ṣe Lè Ṣe É?