July Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé July 2020 Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ July 6-12 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | Ẹ́KÍSÓDÙ 6-7 “Ní Báyìí, Wàá Rí Ohun Tí Màá Ṣe sí Fáráò” July 13-19 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | Ẹ́KÍSÓDÙ 8-9 Fáráò Agbéraga Ò Mọ̀ Pé Ohun Tí Jèhófà Fẹ́ Ni Òun Ń Ṣe MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Jẹ́ Onírẹ̀lẹ̀—Má Ṣe Máa Fọ́nnu MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Jẹ́ Onírẹ̀lẹ̀ Táwọn Míì Bá Ń Yìn Ẹ́ July 20-26 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | Ẹ́KÍSÓDÙ 10-11 Mósè àti Áárónì Lo Ìgboyà MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Ẹ̀kọ́ Wo Làwọn Ohun Tí Ọlọ́run Dá Kọ́ Wa Nípa Ìgboyà? July 27–August 2 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | Ẹ́KÍSÓDÙ 12 Ohun Tí Ìrékọjá Túmọ̀ sí fún Àwa Kristẹni MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Jèhófà Ń Dáàbò Bo Àwọn Èèyàn Rẹ̀