ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb20 July ojú ìwé 5
  • Ẹ̀kọ́ Wo Làwọn Ohun Tí Ọlọ́run Dá Kọ́ Wa Nípa Ìgboyà?

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ẹ̀kọ́ Wo Làwọn Ohun Tí Ọlọ́run Dá Kọ́ Wa Nípa Ìgboyà?
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • “Jẹ́ Onígboyà . . . Kí O sì Gbé Ìgbésẹ̀”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2017
  • Kò Nira Jù Láti Jẹ́ Onígboyà
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • “Jẹ́ Onígboyà Àti Alágbára Gidigidi”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2012
  • Ẹ ní Ìgboyà Dáradára!
    Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1993
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
mwb20 July ojú ìwé 5
Bàbá kan àti ọmọ rẹ̀ dúró lẹ́gbẹ̀ẹ́ odò kan, wọ́n ń wo àwọn òkè tó wà lọ́ọ̀ọ́kán.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Ẹ̀kọ́ Wo Làwọn Ohun Tí Ọlọ́run Dá Kọ́ Wa Nípa Ìgboyà?

Jèhófà ti lo àwọn ọkùnrin àtàwọn obìnrin olóòótọ́ inú Bíbélì láti kọ́ wa láwọn ànímọ́ pàtàkì. Àmọ́, a tún lè kẹ́kọ̀ọ́ lára àwọn ohun tí Ọlọ́run dá. (Jóòbù 12:7, 8) Kí la rí kọ́ nínú bí kìnnìún, ẹṣin, asín igbó, ẹyẹ akùnyùnmù àti erin ṣe nígboyà?

WO FÍDÍÒ NÁÀ KỌ́ ÌGBOYÀ LÁRA ÀWỌN OHUN TÍ ỌLỌ́RUN DÁ, LẸ́YÌN NÁÀ, DÁHÙN ÀWỌN ÌBÉÈRÈ YÌÍ:

  • Kìnnìún kan àtàwọn ọmọ rẹ̀ ń mu omi.

    Báwo làwọn abo kìnnìún ṣe máa ń lo ìgboyà tí wọ́n bá fẹ́ dáàbò bo àwọn ọmọ wọn?

  • Àwọn ẹṣin tó sáré kútúpà-kútúpà.

    Báwo ni wọ́n ṣe máa ń dá àwọn ẹṣin lẹ́kọ̀ọ́ kí wọ́n lè nígboyà lójú ogun?

  • Asín igbó àti ejò ọká jọ wàákò.

    Kí nìdí tí asín igbó kì í fi í bẹ̀rù ejò olóró?

  • Ẹyẹ akùnyùnmù kan ń lé ẹyẹ akùnyùnmù mí ì kúrò ní agbègbè rẹ̀.

    Báwo làwọn ẹyẹ akùnyùnmù kéékèèké ṣe ń lo ìgboyà?

  • Agbo àwọn erin jọ ń rìnrìn àjò.

    Báwo làwọn erin ṣe ń lo ìgboyà nígbà tí wọ́n bá ń dáàbò bo àwọn erin míì nínú agbo?

  • Ẹ̀kọ́ wo làwọn ẹranko yìí kọ́ ẹ nípa ìgboyà?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́