ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 July ojú ìwé 16
  • Kò Nira Jù Láti Jẹ́ Onígboyà

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Kò Nira Jù Láti Jẹ́ Onígboyà
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • “Jẹ́ Onígboyà . . . Kí O sì Gbé Ìgbésẹ̀”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2017
  • Ẹ ní Ìgboyà Dáradára!
    Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1993
  • “Jẹ́ Onígboyà Àti Alágbára Gidigidi”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2012
  • Jẹ́ Kí N Ní Ìgboyà
    “Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 July ojú ìwé 16
Ọ̀dọ́bìnrin kan ń fìgboyà wàásù fún ọmọ kíláàsì rẹ̀, ó ń fi nǹkan hàn án lórí fóònù rẹ̀.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Kò Nira Jù Láti Jẹ́ Onígboyà

Ìgboyà túmọ̀ sí pé kéèyàn láyà, kó jẹ́ ẹni tí kì í ṣojo, kó sì jẹ́ akíkanjú. Ìyẹn ò túmọ̀ sí pé ẹni yẹn ò ní bẹ̀rù rárá. Kàkà bẹ́ẹ̀, ó máa ṣe ohun tó tọ́ tẹ́rù bá tiẹ̀ ń bà á. A lè nígboyà tá a bá gbára lé Jèhófà, torí pé òun nìkan ló lè jẹ́ kéèyàn ní ìgboyà tòótọ́. (Sm 28:7) Báwo làwọn ọ̀dọ́ ṣe lè fi hàn pé wọ́n jẹ́ onígboyà?

Ẹ WO FÍDÍÒ NÁÀ TẸ̀ LÉ ÀPẸẸRẸ ÀWỌN TÓ NÍGBOYÀ, KÌ Í ṢE ÀWỌN OJO! KẸ́ Ẹ SÌ DÁHÙN ÀWỌN ÌBÉÈRÈ YÌÍ:

  • Àwọn ìṣòro wo làwọn ọ̀dọ́ máa ń kojú tó gba pé kí wọ́n nígboyà?

  • Àwọn àpẹẹrẹ wo ló wà nínú Bíbélì tá a lè tẹ̀ lé tá a bá fẹ́ nígboyà?

  • Àǹfààní wo làwa àtàwọn tó ń wò wa máa rí tá a bá jẹ́ onígboyà?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́