ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • sjj orin 153
  • Jẹ́ Kí N Ní Ìgboyà

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Jẹ́ Kí N Ní Ìgboyà
  • “Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • “Jẹ́ Onígboyà . . . Kí O sì Gbé Ìgbésẹ̀”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2017
  • Ẹ ní Ìgboyà Dáradára!
    Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1993
  • “Jẹ́ Onígboyà Àti Alágbára Gidigidi”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2012
  • Kò Nira Jù Láti Jẹ́ Onígboyà
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
Àwọn Míì
“Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
sjj orin 153

ORIN 153

Jẹ́ Kí N Ní Ìgboyà

Bíi Ti Orí Ìwé

(2 Ọba 6:16)

  1. 1. Ìbẹ̀rù ti bò mí​—

    Ìdààmú gbọkàn mi.

    Ọlọ́run jọ̀ọ́ fi mí mọ̀nà;

    Mo mọ̀ pó o máa gbà mí.

    Ìṣòro pọ̀ láyé,

    Ṣùgbọ́n mo gbà gbọ́ pé:

    Atóófaratì mà ni ọ́;

    Ayé mi dọwọ́ rẹ.

    (ÈGBÈ)

    Jèhófà, fún mi nígbàgbọ́

    Kí n lè máa rántí pé

    Àwọn ọ̀tá kò lè borí wa.

    Jọ̀ọ́, jẹ́ kí n nígboyà.

    Kí n sì ṣọkàn akin;

    Kí n fara dà á dópin.

    Jọ̀ọ́, jẹ́ kí n ní ìgboyà;

    Ìwọ ni aṣẹ́gun.

  2. 2. Tí ìbẹ̀rù bá dé.

    Ó ń múni rẹ̀wẹ̀sì.

    Ìwọ làpáta ààbò mi;

    O kì í jáni kulẹ̀.

    Jẹ́ kí n ní ìgboyà,

    Kí n má sì ṣe jáyà.

    Bó ti wù kí ‘ṣòro le tó​—

    Tìrẹ ni màá ṣe láé.

    (ÈGBÈ)

    Jèhófà, fún mi nígbàgbọ́

    Kí n lè máa rántí pé

    Àwọn ọ̀tá kò lè borí wa.

    Jọ̀ọ́, jẹ́ kí n nígboyà.

    Kí n sì ṣọkàn akin;

    Kí n fara dà á dópin.

    Jọ̀ọ́, jẹ́ kí n ní ìgboyà;

    Ìwọ ni aṣẹ́gun.

    (ÈGBÈ)

    Jèhófà, fún mi nígbàgbọ́

    Kí n lè máa rántí pé

    Àwọn ọ̀tá kò lè borí wa.

    Jọ̀ọ́, jẹ́ kí n nígboyà.

    Kí n sì ṣọkàn akin;

    Kí n fara dà á dópin.

    Jọ̀ọ́, jẹ́ kí n ní ìgboyà;

    Ìwọ ni aṣẹ́gun.

    Jọ̀ọ́, jẹ́ kí n ní ìgboyà;

    Ìwọ ni aṣẹ́gun.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́