ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • sn orin 13
  • Àdúrà Ìdúpẹ́

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àdúrà Ìdúpẹ́
  • Kọrin sí Jèhófà
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Àdúrà Ìdúpẹ́
    “Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
  • Jèhófà Bẹ̀rẹ̀ Ìṣàkóso Rẹ̀
    Kọrin sí Jèhófà
  • Jèhófà Bẹ̀rẹ̀ Sí Í Ṣàkóso
    “Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
  • Jèhófà, Ọlọ́run Atóbilọ́lá
    “Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
Àwọn Míì
Kọrin sí Jèhófà
sn orin 13

Orin 13

Àdúrà Ìdúpẹ́

Bíi Ti Orí Ìwé

(Sáàmù 95:2)

1. Jèhófà Olóore, ọpẹ́ yẹ ọ́.

Ìwọ Ọba aláṣẹ la ńké pè.

A tẹrí ba, Olùgbọ́ àdúrà,

A fi ara wa sábẹ́ ìṣọ́ rẹ.

’Joojúmọ́ làṣìṣe ńfàìpé wa hàn;

A ńtọrọ ìdáríjì ẹ̀ṣẹ̀ wa.

Wòó! Ẹ̀jẹ̀ ọmọ rẹ lo fi rà wá.

Ìfẹ́ ọkàn wa ni pé kóo kọ́ wa.

2. Aláyọ̀ làwọn tóo yàn wá sínú

Àgbàlá ìtọ́ni, ìmọ́lẹ̀ rẹ.

F’Ọ̀rọ̀ rẹ kọ́ wa, kí a lè mọ̀ ọ́.

Inú tẹ́ńpìlì rẹ ńbí la fẹ́ gbé.

Ẹ̀rù jẹ̀jẹ̀ lọwọ́ agbára rẹ,

Ó ńfáwa ìránṣẹ́ rẹ nígboyà.

’Jọba rẹ la ńgbé ga Olùgbàlà.

Aó máa wàásù rẹ̀, kì yóò kùnà láé.

3. Jẹ́ kí ojú rere rẹ máyọ̀ kún;

Kí ìjọsìn rẹ dé gbogbo ayé.

O foore dé Ìjọba rẹ ládé,

Àìsàn, ikú òun ’bànújẹ́ pa rẹ́.

Ọmọ rẹ yóò pa ìwà ibi run;

Ẹ̀dá tóo bù kún yóò hó fún ayọ̀.

Kígbe ìṣẹ́gun, Ẹ kọrin ọpẹ́:

“Ìyìn fún Jèhófà, Ọba Ògo!”

(Tún wo Sm. 65:2, 4, 11; Fílí. 4:6.)

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́