ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • bt ojú ìwé 116
  • “Ní Báyìí, Jẹ́ Ká Pa Dà Lọ Bẹ Àwọn Ará Wò”

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • “Ní Báyìí, Jẹ́ Ká Pa Dà Lọ Bẹ Àwọn Ará Wò”
  • “Jẹ́rìí Kúnnákúnná Nípa Ìjọba Ọlọ́run”
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Báwo Ni Àwọn Alábòójútó Àyíká Ṣe Ń Ràn Wá Lọ́wọ́?
    Àwọn Wo Ló Ń Ṣe Ìfẹ́ Jèhófà Lóde Òní?
  • “Ẹ̀mí Mímọ́ Rán Wọn Jáde”
    “Jẹ́rìí Kúnnákúnná Nípa Ìjọba Ọlọ́run”
  • Àwọn Alábòójútó Arìnrìn Àjò—Àwọn Ẹ̀bùn Nínú Ènìyàn
    Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1996
  • Pọ́ọ̀lù “Ń Fún Àwọn Ìjọ Lókun”
    “Jẹ́rìí Kúnnákúnná Nípa Ìjọba Ọlọ́run”
Àwọn Míì
“Jẹ́rìí Kúnnákúnná Nípa Ìjọba Ọlọ́run”
bt ojú ìwé 116
Àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù àti Tímótì dúró sí àjà tó wà lókè nínú ọkọ̀ òkun. Tímótì ń nawọ́ sí ohun kan tó wà lọ́ọ̀ọ́kán bí àwọn òṣìṣẹ́ inú ọkọ̀ òkun náà ṣe ń ṣiṣẹ́.

APÁ 6 • ÌṢE 15:36–18:22

“Ní Báyìí, Jẹ́ Ká Pa Dà Lọ Bẹ Àwọn Ará Wò”

ÌṢE 15:36

Kí ni iṣẹ́ pàtàkì táwọn alábòójútó àyíká máa ń ṣe nínú ìjọ Kristẹni? Àǹfààní wo la máa rí tá a bá fi tọkàntọkàn tẹ́wọ́ gba iṣẹ́ tí wọ́n bá fún wa nínú ètò Ọlọ́run? Báwo la ṣe lè máa fèròwérò lọ́nà tó gbéṣẹ́ látinú Ìwé Mímọ́, kí sì nìdí tó fi yẹ ká jẹ́ kí ọ̀rọ̀ wa bá ipò àwọn olùgbọ́ wa mu? A máa rí ìdáhùn àwọn ìbéèrè yìí àtàwọn ìbéèrè míì bá a ṣe ń ṣàyẹ̀wò ìrìn àjò míṣọ́nnárì ẹlẹ́ẹ̀kejì tí àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù rìn.

Arákùnrin àgbàlagbà kan ń bá àwọn ọ̀dọ́kùnrin méjì sọ̀rọ̀, àwọn mẹ́tẹ̀ẹ̀ta wà nínú mọ́tò.
    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́