ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | MÁTÍÙ 16-17
Èrò Ta Ni Ò Ń Rò?
Bó tiẹ̀ jẹ́ pé ohun tó dáa ló wà lọ́kàn Pétérù, Jésù tètè tún èrò òdí tí Pétérù ní ṣe
Jésù mọ̀ pé àkókò yẹn kọ́ ló yẹ kí òun “ṣàánú” ara òun. Ohun tí Sátánì fẹ́ gan-an ni pé kí Jésù dẹwọ́ ní àkókò pàtàkì yẹn
Jésù jẹ́ ká mọ ohun mẹ́ta tó yẹ ká ṣe tá a bá fẹ́ ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run délẹ̀délẹ̀. Kí ni ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn túmọ̀ sí?
Sẹ́ ara rẹ
Gbé òpó igi oró rẹ
Máa tọ Kristi lẹ́yìn