ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb18 February ojú ìwé 8
  • Yẹra Pátápátá fún Ohun Tó Lè Mú Ìwọ Àtàwọn Mí ì Kọsẹ̀

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Yẹra Pátápátá fún Ohun Tó Lè Mú Ìwọ Àtàwọn Mí ì Kọsẹ̀
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • ‘Kò Sí Ohun Ìkọ̀sẹ̀’ fún Àwọn Tó Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2013
  • Ṣé Wàá Jẹ́ Kí Ọ̀rọ̀ Nípa Jésù Mú Kó O Kọsẹ̀?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2021
  • Kò Sí Ohun Tó Lè Mú Kí Olódodo Kọsẹ̀
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2021
  • Méjì Lára Ìmọ̀ràn Jésù
    Jésù—Ọ̀nà, Òtítọ́ Àti Ìyè
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
mwb18 February ojú ìwé 8

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | MÁTÍÙ 18-19

Yẹra Pátápátá fún Ohun Tó Lè Mú Ìwọ Àtàwọn Míì Kọsẹ̀

Jésù lo àpèjúwe láti kọ́ni nípa bó ṣe léwu tó láti kọsẹ̀ tàbí láti mú kí ẹlòmíì kọsẹ̀.

18:6, 7

  • “Ohun ìkọ̀sẹ̀” túmọ̀ sí ìwà kan tàbí ìṣẹ̀lẹ̀ kan tó mú kí ẹnì kan ṣe ohun tí kò tọ́, kó kọsẹ̀, kó hùwàkiwà tàbí kó ṣubú sínú ẹ̀ṣẹ̀

  • Ó sàn fún ẹnì kan pé kí á so ọlọ ńlá kọ́ ọrùn rẹ̀ kí ó sì bẹ́ sínú òkun ju pé kí ó mú ẹlòmíì kọsẹ̀

Kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ ń yí ọlọ ńlá; wọ́n so ọlọ ńlá mọ́ ọrùn ọkùnrin kan, wọ́n sì jù ú sínú òkun

Ọlọ ńlá

18:8, 9

  • Jésù fún àwọn ọmọlẹ́yìn rẹ̀ nímọ̀ràn pé kí wọ́n mú ohunkóhun tó lè mú wọn kọsẹ̀ kúrò, kódà kó jẹ́ ohun tó ṣeyebíye bí ojú tàbí apá wọn

  • Ó sàn ká pàdánù ohun tó ṣeyebíye bẹ́ẹ̀ ká lè wọ inú Ìjọba Ọlọ́run ju pé kí wọ́n mú wa kọsẹ̀ ká wá lọ parí ayé wa sínú Gẹ̀hẹ́nà, tó ṣàpẹẹrẹ ìparun ayérayé

Àwọn nǹkan wo ni mò ń fi ayé mi ṣe tó lè di ohun ìkọ̀sẹ̀, báwo ni mo ṣe lè yẹra pátápátá fún ohun tó lè mú èmi tàbí àwọn míì kọsẹ̀?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́