ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • th ẹ̀kọ́ 12 ojú ìwé 15
  • Ọ̀yàyà àti Ìfọ̀rọ̀rora-Ẹni-Wò

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ọ̀yàyà àti Ìfọ̀rọ̀rora-Ẹni-Wò
  • Tẹra Mọ́ Kíkàwé Àti Kíkọ́ni
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ìtara
    Tẹra Mọ́ Kíkàwé Àti Kíkọ́ni
  • Jẹ́ Kí Ọ̀rọ̀ Rẹ Wọni Lọ́kàn
    Tẹra Mọ́ Kíkàwé Àti Kíkọ́ni
  • Fífi Ọ̀yàyà Sọ̀rọ̀ Àti Fífi Bí Nǹkan Ṣe Rí Lára Ẹni Hàn
    Jàǹfààní Nínú Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run
  • Sọ̀rọ̀ Bí Ẹni Ń Báni Fọ̀rọ̀ Wérọ̀
    Tẹra Mọ́ Kíkàwé Àti Kíkọ́ni
Àwọn Míì
Tẹra Mọ́ Kíkàwé Àti Kíkọ́ni
th ẹ̀kọ́ 12 ojú ìwé 15

Ẹ̀KỌ́ 12

Ọ̀yàyà àti Ìfọ̀rọ̀rora-Ẹni-Wò

Ẹsẹ Bíbélì tí a tọ́ka sí

1 Tẹsalóníkà 2:​7, 8

KÓKÓ PÀTÀKÌ: Fi ìmọ̀lára tó yẹ sọ̀rọ̀, jẹ́ kí àwọn tó ò ń bá sọ̀rọ̀ mọ̀ pé o nífẹ̀ẹ́ wọn, o sì fẹ́ ràn wọ́n lọ́wọ́.

BÓ O ṢE LÈ ṢE É:

  • Ronú nípa àwọn tó o fẹ́ bá sọ̀rọ̀. Tó o bá ń múra ọ̀rọ̀ rẹ sílẹ̀, ronú nípa àwọn ìṣòro wọn àti bí àwọn ìṣòro yẹn ṣe rí lára wọn.

  • Fara balẹ̀ ronú nípa ohun tó o máa sọ. Jẹ́ kí ọ̀rọ̀ rẹ tura, kó tuni nínú, kó sì fúnni lókun. Má ṣe sọ àwọn ọ̀rọ̀ tó máa bí wọn nínú, má sì ṣe sọ̀rọ̀ àbùkù nípa àwọn tí kì í ṣe Ẹlẹ́rìí Jèhófà àtàwọn ohun tí wọ́n gbà gbọ́.

  • Fi hàn pé o nífẹ̀ẹ́ wọn. Tó o bá sọ̀rọ̀ pẹ̀lẹ́pẹ̀lẹ́ tó o sì ń fara ṣàpèjúwe bó ṣe yẹ, wàá fi hàn pé ọ̀rọ̀ wọn ká ẹ lára. Má ṣe jẹ́ kí ojú rẹ le koko; máa rẹ́rìn-ín músẹ́.

    Àwọn àbá

    Ó dáa kí ìmọ̀lara rẹ ti ọkàn wá, má sì ṣe ki àṣejù bọ̀ ọ́. Tó o bá ń kàwé, gbé ìmọ̀lára tó wà níbẹ̀ yọ, àmọ́ má ṣe pàfiyèsí sí ara rẹ. Fi ohùn pẹ̀lẹ́ gba àwọn tó ò ń bá sọ̀rọ̀ níyànjú.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́