ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • sjj orin 121
  • A Nílò Ìkóra-Ẹni-Níjàánu

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • A Nílò Ìkóra-Ẹni-Níjàánu
  • “Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ó Yẹ Ká Ní Ìkóra-Ẹni-Níjàánu
    Kọrin sí Jèhófà
  • Mímú Eso Ikora-ẹni-Nijaanu Dàgbà
    Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1991
  • Ikora-ẹni-nijaanu—Eeṣe Ti Ó Fi Ṣe Pataki Tobẹẹ?
    Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1991
  • Ẹ Fi Ìkóra-ẹni-níjàánu Kún Ìmọ̀ Yín
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2003
Àwọn Míì
“Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
sjj orin 121

ORIN 121

A Nílò Ìkóra-Ẹni-Níjàánu

Bíi Ti Orí Ìwé

(Róòmù 7:14-25)

  1. 1. A nífẹ̀ẹ́ Jèhófà tọkàntọkàn.

    Àmọ́ ọkàn wa lè máa fà sí ẹ̀ṣẹ̀.

    A gbọ́dọ̀ kóra wa níjàánu,

    Ká lè níyè àti àlàáfíà.

  2. 2. Ojoojúmọ́ ni Èṣù ń dán wa wò,

    Àìpé ara wa sì lè mú wa ṣìnà.

    Ẹ̀kọ́ òtítọ́ ń jẹ́ ká borí,

    Jèhófà sì tún wà lẹ́yìn wa.

  3. 3. Ká máa fọ̀rọ̀ àtìṣe wa yin Jáà,

    Ká má ṣe tàbùkù sí orúkọ rẹ̀.

    Ká wà láìlẹ́bi lójoojúmọ́,

    Ká sì máa kóra wa níjàánu.

(Tún wo 1 Kọ́r. 9:25; Gál. 5:23; 2 Pét. 1:6.)

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́