ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • sjj orin 66
  • Ẹ Kéde Ìhìn Rere Náà

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ẹ Kéde Ìhìn Rere Náà
  • “Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Polongo Ìhìn Rere
    Kọrin sí Jèhófà
  • Àkànṣe Ìní
    “Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
  • Àkànṣe Dúkìá
    Kọrin sí Jèhófà—Àwọn Orin Tuntun
  • Idi Tí A Fi Gbọdọ Mọ Orukọ Ọlọrun
    Orukọ Atọrunwa naa Tí Yoo Wà Titilae
Àwọn Míì
“Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
sjj orin 66

ORIN 66

Ẹ Kéde Ìhìn Rere Náà

Bíi Ti Orí Ìwé

(Ìfihàn 14:6, 7)

  1. 1. Tipẹ́tipẹ́ laráyé ti jogún ẹ̀ṣẹ̀,

    Àmọ́ Jèhófà ṣàánú wa, ó nífẹ̀ẹ́ wa.

    Ó pinnu láti f’Ọmọ rẹ̀ ṣe Ọba wa,

    Àmọ́ ó kọ́kọ́ ṣe ọ̀rọ̀ náà láṣìírí.

    Ó ti wá fi àṣírí náà hàn wá báyìí.

    Láìpẹ́, Ọmọ rẹ̀ máa bẹ̀rẹ̀ sí í

    jọba ayé.

    Jáà ti yan àwọn ẹni àmì òróró

    Tó máa bá Jésù Ọmọ rẹ̀ jọba lọ́run.

  2. 2. Jáà ti ṣètò pé tó bá d’àkókò òpin,

    A máa kéde ìhìn rere yìí fáráyé.

    Àwọn áńgẹ́lì rẹ̀ ń fayọ̀ ràn wá lọ́wọ́;

    Wọ́n ń tì wá lẹ́yìn bá a ṣe ńwàásù òtítọ́.

    Iṣẹ́ pàtàkì ló já lé wa léjìká:

    Ká máa yìn ọ́, ká jẹ́

    kórúkọ rẹ di mímọ́.

    Ọlá ńlá ló jẹ́ bá a ṣe ń jẹ́ orúkọ mọ́ọ.

    Tayọ̀tayọ̀ la ó máa ròyìn rẹ fáráyé.

(Tún wo Máàkù 4:11; Ìṣe 5:31; 1 Kọ́r. 2:​1, 7.)

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́