ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • sjj orin 125
  • “Aláyọ̀ Ni Àwọn Aláàánú”

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • “Aláyọ̀ Ni Àwọn Aláàánú”
  • “Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Aláyọ̀ Ni Àwọn Aláàánú!
    Kọrin sí Jèhófà
  • ‘Baba Yín Jẹ́ Aláàánú’
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2007
  • Ọlọ́run “Tí Àánú Rẹ̀ Pọ̀” Là Ń Sìn
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2021
  • Báwo La Ṣe Lè Máa Ṣàánú Ọmọnìkejì Wa?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2007
Àwọn Míì
“Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
sjj orin 125

ORIN 125

“Aláyọ̀ Ni Àwọn Aláàánú”

Bíi Ti Orí Ìwé

(Mátíù 5:7)

  1. 1. Aláàánú ni Ọlọ́run wa,

    Ó ń yọ́nú síni látọkàn,

    Ó nífẹ̀ẹ́ láti máa ṣoore;

    Kì í fi ohun tá a fẹ́ dù wá.

    Ẹlẹ́ṣẹ̀ tó bá yí pa dà

    Mọ̀ pé Ó máa yọ́nú sáwọn.

    Tor’ó mọ̀ páláìpé ni wá,

    Olóore ni, olóòótọ́ ni.

  2. 2. Bàbá, gbọ́ igbe ẹ̀bẹ̀ wa;

    Ẹ̀ṣẹ̀ mú ọkàn wa gbọgbẹ́.

    K’Ọ́lọ́run lè dárí jì wá,

    Kristi kọ́ wa lóhun tá ó ṣe:

    Pé ká bẹ̀bẹ̀ fún àánú rẹ̀,

    Ká sì lẹ́mìí ìdáríjì.

    Tá a kò bá dira wa sínú,

    A ó máa ní ìbàlẹ̀ ọkàn.

  3. 3. Ká jẹ́ ẹlẹ́mìí ọ̀làwọ́,

    Kí àánú jẹ́ ká máa fúnni,

    Kì í ṣe lọ́nà ṣekárími;

    Ìyẹn máa jẹ́ ká lè láyọ̀.

    Ọlọ́run ń rí wa kedere,

    Yóò san wá lẹ́san ní gbangba.

    Aláyọ̀ làwọn aláàánú;

    Wọ́n lẹ́wà lójú Ọlọ́run.

(Tún wo Mát. 6:​2-4, 12-14.)

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́