ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • ijwfq àpilẹ̀kọ 13
  • Ṣé Ẹ Ní Àwọn Àlùfáà Tí Ẹ̀ Ń Sanwó Fún?

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ṣé Ẹ Ní Àwọn Àlùfáà Tí Ẹ̀ Ń Sanwó Fún?
  • Àwọn Ìbéèrè Táwọn Èèyàn Sábà Máa Ń Béèrè Nípa Ẹlẹ́rìí Jèhófà
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ṣó Yẹ Kí Ìjọ Pín sí Ẹgbẹ́ Àlùfáà àti Ọmọ Ìjọ?
    Jí!—2009
  • Bí A Ṣe Ṣètò Àwọn Ẹlẹ́rìí Jehofa
    Kí Ni Ọlọ́run Ń Béèrè Lọ́wọ́ Wa?
  • Èéṣe tí Àwọn Ẹlẹ́rìí fi Ń Ṣèbẹ̀wò Lemọ́lemọ́?
    Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1994
  • Àwọn Wo Ni Òjíṣẹ́ Ọlọ́run Lóde Òní?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2000
Àwọn Míì
Àwọn Ìbéèrè Táwọn Èèyàn Sábà Máa Ń Béèrè Nípa Ẹlẹ́rìí Jèhófà
ijwfq àpilẹ̀kọ 13
Òjíṣẹ́ kan ń sọ àsọyé Bíbélì

Ṣé Ẹ Ní Àwọn Àlùfáà Tí Ẹ̀ Ń Sanwó Fún?

Àpẹẹrẹ àwọn Kristẹni ọgọ́rùn-ún ọdún kìíní ni àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ń tẹ̀ lé, a kì í ní ẹgbẹ́ àlùfáà àti ti ọmọ ìjọ. Gbogbo àwọn ará wa tó ti ṣe ìrìbọmi jẹ́ òjíṣẹ́ tó máa ń wàásù, tí wọ́n sì ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́. A máa ń pín àwọn ará sínú ìjọ tó máa ń ní nǹkan bí èèyàn ọgọ́rùn-ún [100]. Àwọn ọkùnrin tí òtítọ́ jinlẹ̀ nínú wọn tó wà ní ìjọ kọ̀ọ̀kan ló máa ń sìn gẹ́gẹ́ bí “àgbà ọkùnrin,” tàbí àwọn alàgbà. (Títù 1:5) Wọn kì í sì í gbowó iṣẹ́.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́