Atọ́ka Àwọn Àkòrí fún Jí! 2016
“Ẹ ṣeun tí ẹ̀ ń tẹ àwọn ìwé ìròyìn tó bágbà mu yìí jáde.”—Amy
Ìyá ọlọ́mọ ni Amy, ìwé ìròyìn Jí! sì ti ràn án lọ́wọ́ kó lè máa ṣe ojúṣe rẹ̀ lójoojúmọ́. Bíi ti Amy, ọ̀pọ̀lọpọ̀ èèyàn ti jàǹfààní nínú kíka ìwé ìròyìn tó ń jáde lẹ́ẹ̀kan lóṣù méjì yìí. Lọ sí ìkànnì wa www.jw.org/yo, kó o lè ṣàyẹ̀wò àwọn àpilẹ̀kọ tá a tẹ̀ jáde lọ́dún 2016, bá a ṣe tò wọ́n síbi yìí.
ÀJỌṢE ÀWỌN ÈÈYÀN
Bẹ́ Ẹ Ṣe Lè Yanjú Ọ̀rọ̀ (ìdílé): No. 3
Bí Ẹ Ṣe Lè Dín Wàhálà Kù Nínú Ilé: No. 1
Bí Ẹ Ṣe Lè Mú Kí Àlàáfíà Wà Nínú Ilé: No. 1
Bó O Ṣe Lè Fi Ọ̀wọ̀ Hàn (ìgbéyàwó): No. 6
Bó O Ṣe Lè Ran Ọmọ Rẹ Tó Ń Bàlágà Lọ́wọ́: No. 2
Kí Ló Máa Ń Fa Wàhálà Nínú Ilé? No. 1
Kọ́ Ọmọ Rẹ Nípa Ìbálòpọ̀: No. 5
ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ
ÀWỌN ẸNI INÚ ÌTÀN
ÀWỌN ẸRANKO ÀTI EWÉKO
Ẹ̀SÌN
Ohun Tí Bíbélì Sọ Nípa Kí Ọkùnrin Fẹ́ Ọkùnrin: No. 4
Ṣé Ìsìn ti Fẹ́ Kógbá Wọlé? No. 1
Ṣé Ìwé Tó Kàn Dáa Ni Bíbélì? No. 2
Ṣé Jésù Wà Lóòótọ́? No. 5
ÌFỌ̀RỌ̀WÁNILẸ́NUWÒ
Onímọ̀ Nípa Ọlẹ̀ Ṣàlàyé Ohun Tó Gbà Gbọ́ (Y. Hsuuw): No. 2
ÌLERA ÀTI ÌTỌ́JÚ
ILẸ̀ ÀTI ÀWỌN ÈÈYÀN
Kyrgyzstan: No. 4
OJÚ ÌWÒYE BÍBÉLÌ
Àníyàn: No. 2
Dídé Lásìkò: No. 6
Ẹ̀mí Ìmoore: No. 5
Ẹwà: No. 4
Ìgbàgbọ́: No. 3
Òpin Ayé: No. 1
Ọkàn: No. 1